Mo TV Reality shows

Mo TV Reality shows Please follow for reality show videos and other entertainment news!!! This is not Alhaji Oriyomi or Agidigbo’s page. News and updates
(4)

Follow Agidigbo 88.7 FM, Ibadan to connect with Alhaji Oriyomi

Beautiful Queen Dammy 💕💕💕
09/26/2025

Beautiful Queen Dammy 💕💕💕

The 44th Olubadan of Ibadan, His Imperial Majesty, Oba Rashidi Adewolu Ladoja.Igba yin a tú wa l’ara.Ilufemiloye, we hav...
09/26/2025

The 44th Olubadan of Ibadan, His Imperial Majesty, Oba Rashidi Adewolu Ladoja.

Igba yin a tú wa l’ara.

Ilufemiloye, we have had kings in Ibadan, but this feels different. Congratulations to us, Ibadan! Congratulations 🎉

Interesting story!!! Please read   #   #   #
09/26/2025

Interesting story!!! Please read # # #

Omo oba ni, Oba tun ni, Gomina awon mekunnu!!!Check out Alhaji Oriyomi’s outfit to the Coronation of Olubadan Oba Rashid...
09/26/2025

Omo oba ni, Oba tun ni, Gomina awon mekunnu!!!

Check out Alhaji Oriyomi’s outfit to the Coronation of Olubadan Oba Rashidi Adewolu Ladoja.
Sakiii Omo Oba 💙💙💙

09/26/2025

Lori oro Hammed at Iya Iyawo re # # # # #

Nobody saw this coming!! Singer Shoday linked up with Aminat Obirere, the very legend behind the iconic line 'ki le se m...
09/26/2025

Nobody saw this coming!! Singer Shoday linked up with Aminat Obirere, the very legend behind the iconic line 'ki le se mi, ta ni mo se' that he sampled. He shared a video vining with the queen herself.

From the look of things, a collabo might just be on the way - are you ready for this blend of sounds? # # #

09/26/2025

Ikunle abiyamo!!! Ibon olopa pa omo won ni Ile Ife # # # #

Ibadan, ilú ogbori eléyin, ilú ajéjí kò le gbé!ilú Oluyole,Omo a jíse bí Oyo,Ọmo a gb'ohan s'óri kèrè, kèrè á gbó!Omo a ...
09/25/2025

Ibadan, ilú ogbori eléyin, ilú ajéjí kò le gbé!
ilú Oluyole,
Omo a jíse bí Oyo,
Ọmo a gb'ohan s'óri kèrè, kèrè á gbó!
Omo a ji igbin yóo,
Omo a mu'yan d'erin, erin á sun lóko!
Ibadan gbogbo aye, gbogbo wa la ma yo 🙌👌

Kabiyesi, Iku Baba Yeye, Olubadan of Ibadanland, Oba Rasheed Adewolu Ladoja 👑 💫
On this glorious week of your coronation and on the day of your birth, we celebrate you with joy and pride as children of Ibadan.

Ki ori yin pe l'áye, i ljoye yin dùn bí oyin,
Ibadan máa yo ní àse Olorun.
adan ki í bàjé o, afi olóri bàjé
Happy Birthday and Congratulations, Kabiyesi!
Àgùn bánà gb'ádé, olóye gb'ori adé l'áyò! 🎉

Episode by episode, you will cry in my hands!!!Wahala be like bicycle o 😂 Actress Tosin Olaniyan throws heavy shot at a ...
09/25/2025

Episode by episode, you will cry in my hands!!!

Wahala be like bicycle o 😂 Actress Tosin Olaniyan throws heavy shot at a mystery Aunty producer Isonu based in UK. She used strong words but did not mention and name, from all the coded words she dropped, who do you think she’s talking about? 👀 # #

09/25/2025

Part 4 Iya Asimi so wipe Baba Asimi fi agbon gba Asimi ni ori, la ti igba yen ni wonti n wa Asimi ゚viralシfypシ゚ # # # #

09/25/2025

Part 3 Iya Asimi so wipe Baba Asimi fi agbon gba Asimi ni ori, la ti igba yen ni wonti n wa Asimi ゚viralシfypシ゚ # # # #

09/25/2025

Part 2 Iya Asimi so wipe Baba Asimi fi agbon gba Asimi ni ori, la ti igba yen ni wonti n wa Asimi ゚viralシfypシ゚ # # # #

Address

Abbottvile Road
Concord, NH
03301

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Mo TV Reality shows posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Mo TV Reality shows:

Share