Accurate Gossip

Accurate Gossip EDUCATIVE SHOWS |NEWS |GOSSIP | GISTS
(1)

10/13/2025

1 Kọrinti 1
31 Pe, gẹgẹ bi a ti kọ ọ, Ẹniti o ba nṣogo, ki o mã ṣogo ninu Oluwa.

10/12/2025

Saamu 46
2 Nitorina li awa kì yio bẹ̀ru, bi a tilẹ ṣi aiye ni idi, ti a si ṣi awọn oke nla nipò lọ si inu okun:

10/09/2025

Òwe 22
15 Li aiya ọmọde ni wère dì si; ṣugbọn paṣan itọ́ni ni yio le e jina kuro lọdọ rẹ̀.

10/07/2025

Oluwatoyin ,to know you, is to love you ,have only toyin in your life, she will stood with you, through thick and thin, omo ni Dada Awuru
Thank you for your support and love towards Iyabo Ojo Tv and her children, you are such a wonderful lady, ready to help any time any day ,wa jere awon omo e loruko Jesu, iku ko ni gba omo pa lowo e ,ipa aye ko ni ka yin ,eyin le ma leke gbogbo awon ota yin loruko Jesu, love ❤️ 😍 💖 ❣️ 💕 💘, my love ,I get so much love for you TOYIN ABRAHAM AIMAKU

10/07/2025

Welcome back to your father's land, no shaking, God is with you and awa abiamo totoo is with you, you will eat the fruits of your labor, you will not labor in vain, your joy shall be permanent, you are a great mother, God will bless the work of your hand, wa jere gbogbo awon omo ti oluwa fi fun e loruko Jesu, Welcome back ku ise omo ni se Iyabo Ojo Tv Alice Iyabo Ojo

10/07/2025

Saamu 115
14 Oluwa yio mu nyin bisi i siwaju ati siwaju, ẹnyin ati awọn ọmọ nyin.

10/06/2025

Romu 12
21 Maṣe jẹ ki buburu ṣẹgun rẹ, ṣugbọn fi rere ṣẹgun buburu.

10/02/2025

Ki lo Kan Dada Awuru, omo Kan bi billion TOYIN ABRAHAM AIMAKU🤣🤣🥰🥰🤣🤣🤣🤣🤣

Congratulations Baba and Mama, God will make him a great nation ❤️ Priscilla Ojo Mkambala JUX
10/02/2025

Congratulations Baba and Mama, God will make him a great nation ❤️ Priscilla Ojo Mkambala JUX

10/02/2025

Leave hate alone, celebrate this family, even use them as prayer points, God really show them mercy this year Iyabo Ojo Tv Alice Iyabo Ojo ,you are apple eyes of God and really blessed

10/02/2025

Filipi 4
6 Ẹ máṣe aniyàn ohunkohun; ṣugbọn ninu ohun gbogbo, nipa adura ati ẹbẹ pẹlu idupẹ, ẹ mã fi ìbere nyin hàn fun Ọlọrun.

09/24/2025

Jesu loba ,after him nobody

Address

Houston, TX
77077

Telephone

+14092926992

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Accurate Gossip posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Accurate Gossip:

Share