Yoruba Waves

Yoruba Waves Yoruba Arts And Cultures Invigorating platform

04/25/2025

SO OGUN D’OGOJI. | Check out Yorubawaves LIVE videos on TikTok! Watch, follow, and discover the latest content from Yorubawaves.

04/25/2025

Join us tonight on Yoruba Waves at 8pm Nigerian time on live TikTok as we delve into an insightful discussion on why Nigerians keep falling victims to Ponzi Schemes (SO OGUN DI OGOJI), with a focus on MMM, CBEX etc. We look forward to your participation.
Your presence will be appreciated .

Link will be shared timely.
Thank you.

02/23/2025

Marriage is so beautiful and honorable. Just be Careful about uncontrolled anger, careful about endless insultive talks, careful about receiving advice from evil people, careful not to insult eachother parents, careful about utterance of curse against each other. Upon all, be more patient. But run when it’s become more violent and potentially threatening of life.

A ku Odun keresimesi, Odun a yabo fun gbogbo wa. A se opo Odun laye. A ni fi ibanuje pari Odun yi loruko Jesu. Merry Chr...
12/24/2024

A ku Odun keresimesi, Odun a yabo fun gbogbo wa. A se opo Odun laye. A ni fi ibanuje pari Odun yi loruko Jesu.

Merry Christmas to everyone. May peace fill our hearts as we celebrate many years. May this year end with happiness in Jesus name.

Mo dupe lowo oluwa fun awon Odun to koja. Mo dupe lowo oluwa fun ojo ibi ti Odun yi. Mo dupe fun idasi ati Ore ojojumo. ...
12/18/2024

Mo dupe lowo oluwa fun awon Odun to koja. Mo dupe lowo oluwa fun ojo ibi ti Odun yi. Mo dupe fun idasi ati Ore ojojumo. Ninu Odun yi alafia ni fun mi ati fun ile mi pelu awon afenifere mi. Ki oluwa ba mi wa oko Odun titun yi. Mo ku ojo ibi oni.

I express gratitude to God for the past year. I appreciate the Almighty God for adding another year to my age. I am thankful for life and daily assistance. May peace be upon me, my household, and well-wishers in this year. May God take precedence over everything in this new year. Happy birthday to me.

12/17/2024

Eni tó n wo ohun t’egbé è ní tó n banújé, kó lo wo ohun tí egbé rè dà kó le dúpé. Máse ju ara re lo, jé kí ohun tí o bá ní té o lórùn. Mò wípé, Ohun tí kò tó lòní nbò wá sé kù lóla. Ohun tí kòtó pín nbò wá kárí.

He who got depressed after seeing his equal achievements ,should as well see what has become other peers so he would show appreciation to God. Don’t falsely overdo things, be duly contented with whatever you have.
Know for sure that, what's inadequate today would be surplus tomorrow and that which is insufficient to share, will soon be adequate

12/10/2024

Gbó Òrò ìkìlò: Ikún nje ògèdè nrèdí, ikún ò mò pó’un tó dùn npáni. Gbó òrò ìkìlò nígbàtí ó bá jáde sí o. Òrò wa kòní jé àríkógbón fún elòmíràn.

Heed the warning: :The squirrel is exuberant as it feed on banana, it should have known though that eating sweet stuffs can be deadly. Always heed the warning whenever it comes to you. Our story wouldn’t be a bitter lessons for others to learn from.

12/01/2024

E ká sí Osù kejìlá ,Osù Opé. Nínú Osù titun yí kò ní sí ikú tàbí àrùn. Ìbùkún àti àláfìa wa á di púpò nínú Osù yí. Alafia !


Welcome to the month of December, the thanksgiving month. In this new month there shall be no death or disease. Our Blessings and peace shall be multiplied in this month. Shalom!

11/20/2024

Isé rere: Òjò ìbá rò pa ìgbín, opélopé ìkarahun tó bó mó lè. Isé rere àwon òbí ni ìkarahun tí kò jé k’ójò pa ìgbín àwon omo. Ní ònà tó pò ni àwon omo ti má nje ànfàní lára Isé rere ti àwon òbí won ba se sílè .Ìwo na se Pinnu loni láti se rere kó lè dára fún àwon omo re lójó iwájú. Rántí wípé ,Orúko rere àti Isé rere se pàtàkì ,ó sì kó ipa ribiribi nínú ayé omo ènìyàn

Excellent piece of work: Rain would essentially hurt snail if didn't have its shell which provide protective covering .Great works of parents is a shell which provide protective covering for the children. In many ways ,Children do benefit from good works of their parents. Forget not that ,a strong reputation is essential and it's possesses powerful effects on our lives

11/01/2024

E kábò sí Osù kokànlá tí yorùbá npè ní Osù Bélú. Nínú Osù yí kò ní sí Ikú tàbí àìsàn. Ayò pèlú àláfíà la fi lo gbogbo ojó tó wà nínú Osù yí. Ire, anu àti ìránlówó yíò jé ti wa loruko jesu, Amin.

Welcome to month of November . In this month there shall be no death nor sickness. We shall enjoy all days of this month in exultation and tranquility. Goodness, Mercy and divine help shall be our portion in Jesus name , Amen .

Address

U.S. A
New York, NY
08859

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Yoruba Waves posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Yoruba Waves:

Share