
03/19/2024
AWURE ISE GBIGBA FUN AWON CONTRACTORS ATI ONISE OWO, ATI BEEBE LO.
TI AWON EYAN MA FIN GBE ISE TIA MO ATI EYI TIA KO MO FUN WA.. TI YIO SI YO OWO GIDI.
ISENA RE:-
Ewe Tomato topo ao sa kogbe daada ati odidi atare kan aojo papo, ao lo, ao wa dasi inu 7up odidi kan plastic or bottle, ao se adura gbogbo nkan tia bafe si ao gbemu lekan.. Tio bafe kosise fun oo daadaa koko share si opolopo group, kio si fi comment re se adura fun mi kio to dawo le...
FOLLOW MI LATI JE AWON ORISIRISI ANFANI TOPO NIPA BI ASE NLO EWE ATI EGBO.