15/10/2025
Ti olorun bani ki o ni owo ni owo ju oko re lo , ti Olorun Niki Arisiki gbogbo family wa ni owo ti Iwo Iyawo nikan, Mo fe kio mo.daju wipe Adanwo nla ni olorun fi se fun e , Mosi fe ki o lo mo daju wipe gbogbo Arisiki re ati owo re ti o ni , ko Lee wulo fun e to Oore ti olorun maa se fun awon omo re, , Gbinyanju kio tele awon ilana yi ki Arisiki awon omo re o tun Lee ju tie lo, , number one gbogbo bukata tio ba ye ki oko re o gbo Lori family re Sugbon tiko ni agbara lati yanju awon Bukata naa Sugbon ti olorun Niki agbara Iwo Iyawo o ka bukata naa, ma so fun anybody wipe Iwo Iyawo ni o gbo bukata naa, maa so fun awon omo re wipe daddy won nise Gbogbo e , Number 2 Ma fi ere Ibalopo du oko re Nitori wipe ko ni agbara lati maa gbo bukata, Number 3 Majeki okunrin miran o ri ihoho re Nitori wipe oko re o ni owo ni owo lati se eto re Lori re , Nitori o lewu pupo , Number 4 tio ba je wipe oko re o tii ko ile , Iwo Iyawo wa fee ko ile , gbinyanju kio ko ile naa ni oruko oko re ,ki e wa fi ile yan se family house yin ,Because Ile tio ba ko ni oruko oko re maa se e ni anfani meji , Anfani akoko ni wipe ile eyokan tio ko ni oruko oko re yi maa di ojo ike ojo igbega fun awon omo re ni ola ,,, and then Alubarika ile eyokan yan maa di egberun ile fun awon omo re ni ola , anfani keji ni wipe ti awon Family oko re ba mo wipe oruko oko re ni o fi ko ile re, gbogbo won niwon maa gba fun e , enikeni tio ba wa gbe owokowo Nitori tie ninu family olorun maa ja fun e ni gbogbo ona Nitori otise ife olorun , then gbogbo oore ti olorun bawa se fun e leyin ile family tio ko o le maa fi oruko Ara re sii ,tio basi fe ki Alubarika re o maa po sii o le continue pelu oruko oko re, then tio ba fe ra car oruko oko re Niki o fi raa, ki car Eyokan yan o wa di egberun car fun awon omo re ni ola , number 5 maa se ojuse re ninu ile re , a*o oko re fifo eto re ni, dida ina ounje fun family re ojise re ni , ma so wipe kosi owo ni owo oko re kio wa maa se eyiti o ba wu e, Aisi owo ni owo okunrin ma so Okunrin di Radarada ni gbogbo Igbati awon omo re ba beere nkan tiko Lee fun won ekun asun sinu ni yio maa sun , tiwo mama naa tun bere sini pariwo okunrin radarada tiko Lee toju omo , Sugbon Gbigba fun olorun ni Ara oko re Lee jeki o get Confident re pada, maa dagbere ibiti o ba nlo fun oko re kio to Jade , Nitori ki ojo ale re olee joju daada ninu ola ati alaafia Ara, maa Ranti wipe ati ba olorun duro kun fun kikida egbin ati abukun Sugbon Alubarika Aiye Raye Lori re ati awon omo re ni , Awon ilana ti awon Mama Alalubarika tiwon di mama honorable , tiwon di mama doctor , tiwon di mama governor ni oni niyan , tiwo naa ba si Lee te Le awon ilana yi odaju wipe Atubotan re maa dun, is not how you start that's is matter but how you end up is most important, please stay bless and enjoy the rest of your day, Asalam Alaikum