
31/03/2024
Eyi ni Ijokoo Ramadan Lecture Eyi ti Awon Ajo Ola Olu Muslim Society of Nigeria se Agbekale re ati ni Iranti Baba wa Fadeelatu Shaikh Adiyatullah Bello Alaye (YAAGBOYAJU)
Abe Olohun Ki o bani se Alekun Aforijin fun won Ki o si tewo gba Gbogbo ijosin wa ninu osu Alubarika yi.🙏
Baba wa Al wazeer fun Gbogbo ile Yoruba, Olohun ko ni fi Aare mu yin, Ko si ni jeki ipa Otta o ka yin ati Gbogbo Ololufe Yin
Allahumo Aaamin 😘 🙏