Ìròyìn ní yajoyajo

  • Home
  • Ìròyìn ní yajoyajo

Ìròyìn ní yajoyajo Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ìròyìn ní yajoyajo, News & Media Website, .

07/08/2023

Inú ìlà ìlò ní àwọn ará ìlú Sokoto wà bayi , nitori wahala tó ṣeéṣe kó bẹ sílẹ̀ láàárín nigeria ati naija

Àwọn àjọ ajafeto-omoniyan ni ki ààrẹ Tinubu wa sàlàyé bo sè inu owó orí iranwọ orí èpo
07/08/2023

Àwọn àjọ ajafeto-omoniyan ni ki ààrẹ Tinubu wa sàlàyé bo sè inu owó orí iranwọ orí èpo

07/08/2023

A kú ojúmó óò, ọsẹ yí yíò jẹ́ ọsẹ ayọ funwa l'ase edumare

Ganduje di alága ẹgbẹ́ APC
05/08/2023

Ganduje di alága ẹgbẹ́ APC

Ààrẹ Tinubu tífe gbase lọwọ ile igbimo asofin Naijiria lati ko iko ọmọ ogún ṣòwò sí orílẹ̀-èdè naija
05/08/2023

Ààrẹ Tinubu tífe gbase lọwọ ile igbimo asofin Naijiria lati ko iko ọmọ ogún ṣòwò sí orílẹ̀-èdè naija

01/08/2023

O wù wá kí àgbà ọna míràn láti wojutu sí bí ìlú ṣe lè yí sungbon kòsí ọna abayọ bayi afi ká ní àfaradà fungba diẹ, ààrẹ bọla Tinubu l'ose bẹẹ

25/07/2023

Opo èèyàn gb'emi mi ti awọn kan sí wà ní ẹsẹ kan ayé àti orún leyin tiwon mu oti tan

25/07/2023

Àwọn olùkọ ilé ẹkọ gbogbo nṣe tí ìlú ire faraya lórí ọrọ ọgá àgbà ilẹ ìwé náà ti gomina adeleke fowo osi juwe ile fún,won ni awon kò f'ara mọn ẹni tiwọn yan sipo náà toriwipe ko kunju osunwon

25/07/2023

Ẹgbẹ igbimọ agba APC yíò yanjú òrò ganduje ati ajibola Basiru l'ose yi gẹgẹ bíi alága ati akọwe

Koko iranwo elega mọkanla ni gomina ipinle ogún Dapo Abiodun pe kalẹ lati fi kojú ọrọ owon gogo epo bentiroolu
25/07/2023

Koko iranwo elega mọkanla ni gomina ipinle ogún Dapo Abiodun pe kalẹ lati fi kojú ọrọ owon gogo epo bentiroolu

Ọrọ beyin yọ níbi tí àwọn ará agbègbè kàn ni ìlú ore ti ùn gbon èpo petirolu nigbati ọkọ agbepo kàn fí ẹgbẹ le'lẹ.
24/07/2023

Ọrọ beyin yọ níbi tí àwọn ará agbègbè kàn ni ìlú ore ti ùn gbon èpo petirolu nigbati ọkọ agbepo kàn fí ẹgbẹ le'lẹ.

Alu bámi ojo ni awọn akẹẹkọ ilé ìwé kàn ni ipinle ogun fi Oluko wón ṣe latari pe koje kiwon o ji iwe wo lásìkò ìdánwò
24/07/2023

Alu bámi ojo ni awọn akẹẹkọ ilé ìwé kàn ni ipinle ogun fi Oluko wón ṣe latari pe koje kiwon o ji iwe wo lásìkò ìdánwò

Address

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ìròyìn ní yajoyajo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

  • Address
  • Alerts
  • Claim ownership or report listing
  • Want your business to be the top-listed Media Company?

Share