
20/03/2025
Kóòtù fagilé ẹjọ́ Oriyomi àti Naomi, wọ́n kò lẹ́jọ jẹ́ mọ́
Ṣé Oriyomi àti Naomi san owó gbà má bínú fáwọn òbí ọmọ tí wọn tẹ̀ pa?
Kí ni agbẹjọ́rò àgbà ìpínlẹ̀ Oyo sọ nílé ẹ́jọ́?
Kí ni adájọ́ rò tó fi bọ́ òkùn ẹ̀wọ̀n lọ́rún Oriyomi àti Naomi?
Ọ̀pọ̀ ìdáhùn sáwọn ìbéèrè yìí ló wà nínú ìròyìn yìì àti ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn nípa bí ìgbẹ́jọ́ Oriyomi àti Naomi Silekunola ṣe lọ ní Ibadan lónìí