
04/08/2025
ALAAMU OKIN ALAGBO IGBORO,
ALAAMU TO SOGBO DILE, OSOGBE DI GBORO,
BABA AMA SOWIPE MI O NI GBA ILE ONILE, MIO NI GBE ARA ITA LORI OMO ILU OSOGBO.
GBOGBO ILU OSOGBO N SE IRAN TI RE OOOOOOO
ALAAMU OKIN, 😂 ODI GBERE OOOOOOOOO
😂😭🤣
EYI NI IRANTI OBA WA ANA,
LATI ILE ISE ALALAYE RADIO TV 📺
COTONOU BRANCH