Àsà àti ìse ilè yorùbá

Àsà àti ìse ilè yorùbá orí ìkànnì yìí wà fún kíkó àti kíka èdè yorùbá
àti ìjàngbara fún orílẹ̀ èdé Yorùbá .
(2)

Ayẹyẹ Àjọ̀dún Àádọ́rin Ọdún ìlú Ajọwa  Àkókó  yóò bẹ̀rẹ̀ ni ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n 29 /9 /2025Àṣèyí Sàmọ́dún oo 🙏❤️👇
17/09/2025

Ayẹyẹ Àjọ̀dún Àádọ́rin Ọdún ìlú Ajọwa Àkókó yóò bẹ̀rẹ̀ ni ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n 29 /9 /2025
Àṣèyí Sàmọ́dún oo 🙏❤️👇

17/09/2025

Ìfẹsẹ̀wọ́sẹ̀ eré bọ́ọ́lù gbogbo ilẹ̀ Adúláwò yóò wáyé ní

17/09/2025

ỌWỌ́ TI TẸ ÀWỌN FÚLÀNÍ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ TÓ PA WỌN NÍ ÌLÚ Ẹ̀GBẸ̀, KABBA YAGBA WEST Ò! 🙆👇

16/09/2025

Oníwàásù gbọ́dọ̀ gba àṣẹ lọ́wọ́ ìjọba kó tó sọ̀rọ̀ lórí ohunkóhun

Ijoba ti yọ ènìyàn milionu mẹ́wàá kúrò nínú ìṣẹ́ àti òsì

16/09/2025

ELÉDÙMARÈ Á FI IRE WÁ GBOGBO WA RÍ KÍ Ọ̀SẸ̀ YÌÍ TÓ PARÍ 🙏

16/09/2025

Ó DOJÚ Ẹ! ÀWỌN Ọ̀DỌ́ ÌLÚ ELEYIN ISIN ÌPÍNLẸ̀ KWARA TI YARÍ MỌ́ ÀWỌN OLÓGUN BÍ ÀWỌN AGBÉSÙNMỌ̀MÍ ṢE Ń JÍ ÀWỌN ÈNÌYÀN GBÉ 👇🙆

14/09/2025

ÀWỌN Ọ̀DỌ́ ÌLÚ Ẹ̀GBẸ̀ TI YARÍ Ò! BÍ ÀWỌN AGBÉSÙNMỌ̀MÍ ṢE Ń PA WỌN 👇

14/09/2025

Ẹ wá gbọ́ ìwàásù tí AGBÉSÙNMỌ̀MÍ se fún àwọn ènìyàn tí wọ́n jí gbé 👇🙆

Ẹ JẸ́ KÍ Á MA WO ÀWỌN OÚNJẸ TI A Ń RÀ JẸ DÁADÁA OA Ò NÍ ṢÌ JẸ TỌMỌTỌMỌ O 🙏👇😭
14/09/2025

Ẹ JẸ́ KÍ Á MA WO ÀWỌN OÚNJẸ TI A Ń RÀ JẸ DÁADÁA O
A Ò NÍ ṢÌ JẸ TỌMỌTỌMỌ O 🙏👇😭

Ẹ BÁ MI ṢE ÀDÚRÀ FÚN  FÚN AYẸYẸ ỌJỌ́ ÌBÍ TÍ WỌN Ń ṢE LÓNÌÍ Ẹ̀MÍ YÍN A ṢE Ọ̀PỌ̀ ỌDÚN LÁYÉ ÌGBÀ ỌDÚN, ỌDÚN KAN NI NÍNÚ AYÒ...
14/09/2025

Ẹ BÁ MI ṢE ÀDÚRÀ FÚN FÚN AYẸYẸ ỌJỌ́ ÌBÍ TÍ WỌN Ń ṢE LÓNÌÍ Ẹ̀MÍ YÍN A ṢE Ọ̀PỌ̀ ỌDÚN LÁYÉ ÌGBÀ ỌDÚN, ỌDÚN KAN NI NÍNÚ AYÒ ÀLÀÁFÍÀ ÀÌKÚ TÍ Í ṢE BAÁLẸ̀ ỌRỌ̀ LÁṢẸ ÈDÙMÀRÈ🙏 🎊🎉🎉🎁🎊🎉🎉🎉

13/09/2025

ÈYÍ LOHUN TÓ ṢẸLẸ̀ NÍ ÀÀFIN ỌBA GEGUN AYETORO ÒKÈ Ọ̀YỌ́ 👇

ÈYÍ NI BÍ ÌGBOHO ÒÒṢÀ ṢE S'ÀBẸ̀WÒ SÍ ÀÀFIN ỌBA ASEYIN TÌLÚ ISEYIN ÒKÈ OGUN ÌPÍNLẸ̀ Ọ̀YỌ́ 👇❤️FÚN ÈTÒ ÀBÒ ILẸ̀ KÁÀRỌ̀ Ò JÍ...
13/09/2025

ÈYÍ NI BÍ ÌGBOHO ÒÒṢÀ ṢE S'ÀBẸ̀WÒ SÍ ÀÀFIN ỌBA ASEYIN TÌLÚ ISEYIN ÒKÈ OGUN ÌPÍNLẸ̀ Ọ̀YỌ́ 👇❤️FÚN ÈTÒ ÀBÒ ILẸ̀ KÁÀRỌ̀ Ò JÍRE

Address

Casablanca
20230

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Àsà àti ìse ilè yorùbá posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Àsà àti ìse ilè yorùbá:

Share