AsunkyTainment

AsunkyTainment Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from AsunkyTainment, Digital creator, Obada, Abeokuta.

"Get entertained, informed, and inspired with AsunkyTainment Radiovision! 🎉 We're your go-to online media destination for the latest news, laughs,
📲 Follow for daily vibes.

IRAWO OMI AGBARA CANCER CANCER 🦀  (June 22 - July 22)Awon oni irawo je alagbara eda akanda eledumare ni won.Omo elegbe l...
09/09/2026

IRAWO OMI AGBARA CANCER
CANCER 🦀 (June 22 - July 22)

Awon oni irawo je alagbara eda akanda eledumare ni won.

Omo elegbe lopoju ninu awon oni irawo yi toripe agbalagba omo lo ma npoju ninu won.

Irawo yi je irawo ebi family leyi toje wipe won ma nnife awon ebi won family.

Won je irawo ti won ma ndabobo awon ebi family won, won situn je irawo tin nma nnife awon omo ti won babi pupo.

Moon osupa ni planet tandari awon oni irawo yi leyi totumo si wipe imole tin ntana sinu okunkun ni awon oni irawo yi je, awon oni irawo yi gbodo soro fun mimo se nkan okunkun, toripe otako kadara won.

Ki awon oni irawo yi sora fun ki won ma wo a*o tiko ba irawo won mu, toripe ifaseyin ni yio ma fa fun won.

Awon oni irawo yi won kogbo ma sun sinu okunkun ki won ma ba pa ina ogo won.

Oni irawo yi tin ba se nkan eewo irawo re ati akosejaiye re, wahala ma npo fun iru eniyan be , bi iru eniyan be ba nse kuro ninu isoro kan ni yio ma bo sinu isoro miran toripe otin se nkan totako irawo re ati akosejaiye re.

Ki awon oni irawo yi lo mo nipa awon nkan toje eewo irawo won , ki won ma ba pa ina ogo won.

irawo omi agbara ma saba duro ti eniyan won kin wu iwa odale,

Awon oni irawo yi ni agidi pupo ti inu mi ni ma se po fun won, won gbodo sora fun ibinu toripe ibinu ma nba nkan je fun won ni.

Awon oniirawo omi agbara Cancer ♋️ won je eleyin ju anu, be de ni oro awon eniyan ma ta won lara.

Awon oni irawo yi ma ni isoro ogun idile leyi toye ki won mu oju to ki won leba ri aiye gbe.

Awon oni irawo yi ma nni isoro ile oko leyi toje wipe pupo ninu won ma nka ile oko kiri,

suru ni awon oni irawo yi file gbe ile oko le figbe

Awon ti won nlo irawo yi akanda eniyan ni won je alagbara eniyan ni won.

Ki awon ti won nlo irawo yi ki won sora fun ibinu nitori ki won maba ma fi owo ara won se rawon.

irawo omi agbara yi ko dara fun won ki won ma sun ni okunkun Okunkun ko ba irawo won mun.

irawo omi agbara yi ki won ma wo a*o funfun daada koda ki won ma fi sun ati te si b

Happy new month.
01/09/2026

Happy new month.

BI A S̩E NKI AWO̩N ONIRUNRU OSIS̩E̩ NI ILE̩ YORUBA (E je ki awon Omo wa mo nkan won yii) asa wa ni ede wa, Ogo Ile Yorub...
31/08/2026

BI A S̩E NKI AWO̩N ONIRUNRU OSIS̩E̩ NI ILE̩ YORUBA

(E je ki awon Omo wa mo nkan won yii)
asa wa ni ede wa,
Ogo Ile Yoruba ko ni parun.

Ase o.

*1. ALAGBE̩DE̩*
Ikini: Aro̩ye o!
Idahun: Ogun agbe wa o!

*2. AGBE̩*
Ikini: Aroko bo̩dun de!
Idahun: Ase. Adupe̩.

*3. AKO̩PE̩*
Ikini: Igba aro̩ o! E̩ mo̩şe o!
Idahun: Ase. Adupe̩ o

*4. ONIDIRI.*
Ikini: Oju gbooro/E̩ ku e̩wa
Idahun: Oya ya o. Iyemo̩ja agbe o.

*5. ONIS̩OWO*
Ikini: Aje a wo̩ gba o!
Idahun: Ase o. Adupe̩ o

*6. O̩LO̩DE̩*
Ikini: Ogun afowo jona o
Idahun: Arinpa nt’ogun o

*7. BABALAWO*
Ikini: Abo̩rubo̩ye ni le Ifa
Idahun: Abo̩ye bo̩ s̩i s̩e̩. Ifa a gbe wao.

*8. ONIS̩E̩ OLUWA ALUFA/WOLI*
Ikini: E̩ku is̩e̩ Oluwa, Oluwa yio so̩
agbara d’o̩tun o!
Idahun: Amin o.

*9. ONILU*
Ikini: Aluye o
Idahun: Ase o

*10. OLOYUN*
Ikini. Aso̩kale̩ ayo̩.
Agbo̩ ohun iya. Agbo̩ ohun o̩mo̩
Idahun: Ase o! Ire akari o!

Follow page yi fun update

28/08/2026

Tani Olohun Thanks Nigerians

Tani Olohun has thanked Nigerians, especially the people of Ibadan and Chief Sunday Igboho, for standing by him during the attempted illegal arrest by Ilorin Police.

The arrest was unsuccessful due to community intervention, jurisdictional concerns and the need for proper coordination and due process.

He appreciates everyone who supported him and helped prevent the situation from going out of hand

IRAWO ERUPE FUNFUN VIRGO ♍️ PART 1(AUGUST 23 -  SEPTEMBER 22)Awon oni irawo yije olola eniyan, planet to njoba Irawo yi ...
27/08/2026

IRAWO ERUPE FUNFUN VIRGO ♍️ PART 1
(AUGUST 23 - SEPTEMBER 22)

Awon oni irawo yije olola eniyan, planet to njoba Irawo yi ni (mercury) Irawo aje wealth ni irawo yi je, olokiki eniyan, olola,olowo ni won ma nje laiye

Dandan ni owo (money) lado awan oni irawo yi toripe Irawo aje ni won lo, won situn ma ntete ni owo lowo ayafi eniti Idiwo aiye bawa larare abi enito nba nse nkan totako Irawore ati kadarare iru eniyan be yio le fun lati tete ri ogore lo ayafi ti oba mu oju to oro aiyo nikan loku.

awon oni Irawo yi ma nni ogun ota pupo bena sini awon agbalagba ma ndamu won pupo leyi toye kiwon tete mojuto laaro aiyo won ki awon aiye leje ki won ri aje arawon lo.

awon oni irawo yi ma nje eewo Irawo ati kadara won leyi toma nfa wahala ati idamu Sinu aiye won, nkan ti ofise pataki fun won niyen lati lo ma nipa asiri Irawo won ati akosejaiye won,

kiwon maba si ese gbe ni aro aiye won toripe pupo ninu won ni won ma si ese gbe gan laroo aiye won latari aimo nipa asiri aiye won ati awon nkan totako irawo won ati akosejaiye won ,

eyi ni omanfa ti won ma fi ri opolopo wahala ati idamu ninu Irin ajo aiye won kiwon to laaluyo laiye,

fun Iwo ti oba fe tete de ibiti onlo laiye laini si wahala ati idamu fun o ninu irin ajo aiye re, lomo nipa asiri irawo re ati akosejaiye re,

eyiyi ni yio je kio tete ri ogore lo laiye toripe irawo yi gba amojuto gan , kiwon leba tete ri ogo won lo laiye ati wipe kiwon leba tun ri ebun (gift) ti olohnun fun won lo.

Iranse olohun ni awon oni irawo yi Je pupo ninu won ni won ni ebun ala ati emi iriran, olohun tunma nLo won fun Ise lyanu re.

awon oni Irawo yi je olopolo pipe eniyan akikanju eniyan ni won je, awon oni-irawo yi ma nsise karaka won kinse ole rara (Lazy)

-awon oni irawo yi lawo gidigan ,oloju anu ni pupo ninu won.

eniyan ti ose gbe okanle ni won , won o Kinse odale eniyan, awon eniyan ni won ma ndale won eyiyi ni ofiye ki won sora. ki won mo iru eniyan ti won Maba se .

bi awon onirawo yi se je omo alaje, olowo, olola bajumo to, Irin ajo aiye won ki saba ya won , nkan man le (difficult) fun won pupo be sini ati dide laiye ama le fun won gan,

idi ni yi tio fise pataki fun gbogbo iwo ti oba lo iru irawo yi kio mu ojuto oro aiye re daadaa kio la ba ri ogore lo laiye,

toripe awon omo ti ababi sinu irawo yi ogo Idile ni won ma nje ati Idile na sini ogun aiye won tinma nbere afi eyi ti oba Jina si Idile re tio si mu oju to oro aiyere ni yiio tete ri ogore lo.

Asiri po ni Abe irawo yi ti akole sotan die ni nkan ti a*o nibe fun iwo ti oba fe mo nipa asiri topamo si Abe irawo re awon eewo irawo re nkan to ye kio ma se ati nkan tiko ye kio ma se ti wa fi tete de ibi ogore message me privately.

Ose pataki fun gbogbo eniyan lati mo nipa irawore ati akosejaiyere kio le ba mo bi wa se rin irin ajo aiyere.

Osepataki fun gbogbo eniyan lati mo nipa irawore toripe itosona ni irawo je fun gbogbo eniyan lati letete de ibi ogore.

Gbogbo irawo kokan ni won ni eewo ti won, toye ki won jina si bena situn ni nkan tio ye kiwon mase ti won fi tete de bi ogo won.

Ti eniyan ba nse nkan totako irawo re abi onfun irawo re ni eewo je iru eniyan be yio le fun lati tete de ibi ogore toripe gbogbo irawo kokan ni won ni awon emi ti won ba won sise awon emi yi oluranlowo ni won je, iwo ti oba tifun won ni eewo je abi o mo awon nkan toroma irawo re ti ofin wa nse nkan totako irawo re awon emi yi ma jina sio ti awon emi yi ba siti jinna si eniyan nkan yio bere sini daru fun iru eniyan be, bio se ogun ko ni sise promise and fail yio situn mada iru eniyan be lamu iwo ni kiolo se iwadi arare koma ba waiye asan.

Ose pataki fun o lati lo mo nipa irawo re kio leba tete ri ona lo.

Osepataki fun gbogbo eniyan lati mo nipa irawore toripe itosona ni irawo je fun gbogbo eniyan lati letete de ibi ogore.

Gbogbo irawo kokan ni won ni eewo ti won, tio ye ki won jina si bena situn ni nkan tio ye ki won mase ti won fi tete de bi ogo won.

FUN IWADI LORI IRAWO ATI AKOSEJAYE follow this page.

26/08/2026

"Taiwo Hassan death was a big blow to me, he was everything i had" ~ Ajoke Taiwo a.k.a Iya Jésù

26/08/2026

Ogogo in action
Farewell baba.

This is sad 💔 Kunle Afod paid a visit to Baba Opebe, and he described the condition he met him in as terrible.  Baba Ope...
25/08/2026

This is sad 💔 Kunle Afod paid a visit to Baba Opebe, and he described the condition he met him in as terrible.

Baba Opebe revealed that he has been battling illness for over a year. According to him, doctors said he has a shortage of blood. He has received 4 pints of blood and done several tests, but there has been no improvement.

During the visit, Kunle Afod gave him ₦100,000 to help with his needs.

Please, Baba Opebe needs our help.
Baba Opebe needs our prayers.
These are the veterans who paved the way for Nollywood today and brought so much joy to our faces with their craft.

If you know any hospital or trusted traditional healer that can help treat him, kindly recommend.

GreenPasture Homes Building affordable housing for all.
25/08/2026

GreenPasture Homes
Building affordable housing for all.

20/08/2026

ÀWÒRÁN

Address

Obada
Abeokuta
110101

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when AsunkyTainment posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share