Ẹwà Èdè Yorùbá TV

Ẹwà Èdè Yorùbá TV Entertainment, Comedy, Cultural Heritage, Mother Language, Extensive Yoruba Language and culture

07/07/2025

Àgbọ̀n - Jaw
Agbọ̀n - Basket
Àgbọn - Coconut
Agbọ́n -?

Kíni "Screen" ní èdè Yorùbá?
05/07/2025

Kíni "Screen" ní èdè Yorùbá?

01/07/2025

Ilá - Okro
Ìlá - Town
Ilà - Tribal Mark
Ìlà -?

Kíni "Transmission" ní èdè Yorùbá?
27/06/2025

Kíni "Transmission" ní èdè Yorùbá?

23/06/2025

Ẹyín - Tooth
Ẹ̀yìn - Back
Ẹyin - Egg
Ẹyìn - ?

Kíni "Shares" ní èdè Yorùbá?
19/06/2025

Kíni "Shares" ní èdè Yorùbá?

17/06/2025

Eré - Play
Ère - Statue
Èrè - Profit
Erè - ?

Kíni "Measurement" ní èdè Yorùbá?
13/06/2025

Kíni "Measurement" ní èdè Yorùbá?

Alahji Moshood Kashimawo Olawale Abiola...Ìtẹ́ tí a kò jókòó sí Ipò tó tọ́ tí a kò dé Ìjọba àwa arawa tí a kò gbà láàyè ...
12/06/2025

Alahji Moshood Kashimawo Olawale Abiola...

Ìtẹ́ tí a kò jókòó sí
Ipò tó tọ́ tí a kò dé
Ìjọba àwa arawa tí a kò gbà láàyè
June 12, 1993, ọ̀jọ́ málegbàgbé

11/06/2025

Ọpẹ́ - Thanks
Ọ̀pẹ - Palm tree
Òpè - ?

Kíni "BONUS" ní èdè Yorùbá?
09/06/2025

Kíni "BONUS" ní èdè Yorùbá?

07/06/2025

Gbólóhùn onípọ́nná
Ibi - Place
Ibi - Placenta
Ibi - ?

Address

Adebayo
Ado-Ekiti

Telephone

+2348064041568

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ẹwà Èdè Yorùbá TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Ẹwà Èdè Yorùbá TV:

Share