AARE Ayinla entertainment

AARE Ayinla entertainment Nigeria

19/08/2025

When God is your source, no one can stop your progress. Chanting before the great king HIM Oba Abimbola Owoade Akanni Oòṣà, but all praise to God.
Ọmọ yín, ọ̀rẹ́ yín, Olólùfẹ́ yín, Ààrẹ Àyìnlá yín náà ni... Bí ẹ̀mí ò bá bọ́
Ire ń bẹ
Hìn-ìn hín-ìn
Ire ń bẹ 🙏🙏🙏

👌👌👌Congratulations to our new Excos Handing over 23rd July 2025 was bittersweet, but I'm excited for the future. Glory t...
28/07/2025

👌👌👌
Congratulations to our new Excos
Handing over 23rd July 2025 was bittersweet, but I'm excited for the future. Glory to God for His guidance🙌 🙏

Àwa náà di former DOC nìyẹn 🫣
Ìgbà lẹ̀wù
Oyè ti kúrò ní ti ará Awó, ó ti dé Màpó-Àrógun.

Ta ló ń ráńṣẹ́ ikú sí Sheikh Majeed Aláwayè ní ìlú Ọ̀yọ́??Ta ni ẹ fura sí? Kínni ẹ̀ṣẹ̀ Aláwayè?
25/03/2025

Ta ló ń ráńṣẹ́ ikú sí Sheikh Majeed Aláwayè ní ìlú Ọ̀yọ́??

Ta ni ẹ fura sí?
Kínni ẹ̀ṣẹ̀ Aláwayè?

24/03/2025

May you marry a woman who behaves exactly like your mother🙏🙏🙏

21/03/2025

We finally lost him😭😭😭
We finally lost her 😭😭😭
These words shall never be heard in your family
🙏🙏🙏

APPRECIATION ✍️APPRECIATION ✍️ ✍️ APPRECIATION ✍️ ✍️ ✍️ To the Almighty God, I offer my deepest gratitude for the succes...
08/03/2025

APPRECIATION ✍️
APPRECIATION ✍️ ✍️
APPRECIATION ✍️ ✍️ ✍️

To the Almighty God, I offer my deepest gratitude for the success of our induction ceremony.

To our esteemed guests, lecturers, and well-wishers, I thank you for honoring us with your presence. Your support and encouragement mean the world to me.
Special appreciation goes to our Vice Chancellor, HOD and lecturers from the Department of Linguistics and African Languages, Obafemi Awolowo University, for their kind words and recognition of our efforts.
To our awardees, I congratulate you on this well-deserved recognition:
- Prof. Taiwo Gbolagade (Provost, Adekunle Ajasin University)
- General Ismo Alhaji
- Chief Fatai Oodua Lalude
- Hon. Popoola Ibrahim Alaba Alabama
- Chief Samuel Ibikunle ArúgbóBọ́ìsì
- Chief Okiki Ifa
- Chief Ifaseyi Adeoye Ajanaku Ọrunmila
- Chief Abdul-Hakeem Abdul-Hameed Erankere
- Chief Ifagbensola Awurela-agbaye
- Hon. Ibrahim Olamilekan Akéwì àgbáyé

I also extend my gratitude to our special guest artists, including Special ACTOR LALAA and other talented actors.
To my committee members, I thank you for your tireless efforts and dedication to making this event a success.
And to our inductees, I congratulate you on this milestone achievement.

May God bless and guide us all.
Thank you.

Olaniyi Yusuff Olalekan (Ààrẹ)
Director of Culture (DOC), Obafemi Awolowo University, Ile-Ife.











20/11/2024

Òwúyẹ́ òní
Ilé à-wò-ṣí-fìlà ò níí ṣàìdàlàpà lọ́la.
Ìgbà layé. Àsìlò dúníyàn ò níí ṣàìgbomijé lójú ẹni lọ́jọ́ alẹ́.
🔥À🔥à🔥r🔥ẹ🔥

20/11/2024

ÒWÚYẸ́ ÒNÍ
Pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ là á pa àmúkùrù abẹ́ ẹpọ̀n.

Orí kunkun níí mú ikú àmúkùrù pa ẹni lẹpọ̀.
🔥À🔥à🔥r🔥ẹ🔥

😭🕯️😭🕯️😭🕯️😭Oró ńlá lèyí nínú ilé GAWAT Rukayat olórin Islam di àkọlẹ̀bọ̀ Lẹ́yìn tí bàbá di àwátì ní ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn.Ó m...
24/09/2024

😭🕯️😭🕯️😭🕯️😭
Oró ńlá lèyí nínú ilé GAWAT
Rukayat olórin Islam di àkọlẹ̀bọ̀
Lẹ́yìn tí bàbá di àwátì ní ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn.
Ó mà ṣe o

21/09/2024

Nǹkan ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ikú Aláàfin 😂😂😂

13/08/2023

Thank you Lord for giving me all 🙏🙏🙏

07/05/2023

Watch out for my interview with TOMIZ MEDIA 🔥🔥🔥🔥

Address

Apapa

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when AARE Ayinla entertainment posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category