DBC.News.Yoruba

DBC.News.Yoruba DBC.Africa.Television

Eyin ti DBCNewsYoruba eku odun  tuntun 2024 emi wa yoo se pupo re laye igba odun odun kan ni fun wa./DBCNewsYoruba
01/01/2024

Eyin ti DBCNewsYoruba eku odun tuntun 2024 emi wa yoo se pupo re laye igba odun odun kan ni fun wa./DBCNewsYoruba

Owo olopaa ipinle eko te awon afurasi meta kan ti won loji Cable ina monamona ni agbegbe Muritala Muhammed Airport niluu...
31/07/2023

Owo olopaa ipinle eko te awon afurasi meta kan ti won loji Cable ina monamona ni agbegbe Muritala Muhammed Airport niluu Eko./DBC.News.Yoruba

Egbe osise ni ipinle oyo NLC se iwode lonii won si gbe abawole sekiteriati ijoba ti pa lori bi nkan se nlo ni Naijiria./...
31/07/2023

Egbe osise ni ipinle oyo NLC se iwode lonii won si gbe abawole sekiteriati ijoba ti pa lori bi nkan se nlo ni Naijiria./DBC.News.Yoruba

Aare Asiwaju Bola Ahmed Tinubu yoo ba awon omo Naijiria soro lago meje ale oni./DBC.News.Yoruba
31/07/2023

Aare Asiwaju Bola Ahmed Tinubu yoo ba awon omo Naijiria soro lago meje ale oni./DBC.News.Yoruba

Ajo NLC yoo bere iyanselodi lojo keji osu kejo odun yii./DBC.News.Yoruba
31/07/2023

Ajo NLC yoo bere iyanselodi lojo keji osu kejo odun yii./DBC.News.Yoruba

Egbe awon dokita NARD so pe iyanselodi awon yoo ma tesiwaju t**i ti ijoba yoo fi se awon ohun ti awon n fe
31/07/2023

Egbe awon dokita NARD so pe iyanselodi awon yoo ma tesiwaju t**i ti ijoba yoo fi se awon ohun ti awon n fe

Ewo aworan ayeye eto isinku Ogagun Oladipupo Diya ti won se nile ijosin Saint Paul Cathedral Church to wa nilu odogbolu ...
31/07/2023

Ewo aworan ayeye eto isinku Ogagun Oladipupo Diya ti won se nile ijosin Saint Paul Cathedral Church to wa nilu odogbolu l'ipinle ogun./DBC.News.Yoruba

Egbe awon dokita NARD so pe Iyanselodi awon yoo tesiwaju t**i ti ijoba yoo fi se awon ohun ti awon fe./DBC.News.Yoruba
31/07/2023

Egbe awon dokita NARD so pe Iyanselodi awon yoo tesiwaju t**i ti ijoba yoo fi se awon ohun ti awon fe./DBC.News.Yoruba

Awon ologun gbajoba mo Bazoum lowo lorile-ede Niger./DBC.News.Yoruba
31/07/2023

Awon ologun gbajoba mo Bazoum lowo lorile-ede Niger./DBC.News.Yoruba

Awon araluu ipinle Adamawa yawo ibi ti ijoba ko awon ounje si ti won si ko awon ounje ibe lo lataari owongogo ounje to w...
31/07/2023

Awon araluu ipinle Adamawa yawo ibi ti ijoba ko awon ounje si ti won si ko awon ounje ibe lo lataari owongogo ounje to waye lorile-ede Naijiria./DBC.News.Yoruba

Olori egbe ajijagbara IPOB Nnamdi Kanu ti pase fawon alatileyin re pe ki won maa sise lojo aje pada./DBC.News.Yoruba
31/07/2023

Olori egbe ajijagbara IPOB Nnamdi Kanu ti pase fawon alatileyin re pe ki won maa sise lojo aje pada./DBC.News.Yoruba

Ewo aworan ayeye odun Elegba ti odun 2023 ti won se ninu aafin Oba Saheed Ademola Elegushi l'ilu Eko.DBC.News.Yoruba
31/07/2023

Ewo aworan ayeye odun Elegba ti odun 2023 ti won se ninu aafin Oba Saheed Ademola Elegushi l'ilu Eko.DBC.News.Yoruba

Igbakeji Aare Naijiria Alhaji Kashim Shettima sabewo sibi ayeye eto isinku Otunba Subomi Balogun nilu ijebu ode l'ipinle...
08/07/2023

Igbakeji Aare Naijiria Alhaji Kashim Shettima sabewo sibi ayeye eto isinku Otunba Subomi Balogun nilu ijebu ode l'ipinle ogun./DBC.News.Yoruba

Ewo aworan ibi ti won ti gbe oku ologbe Otunba Michael Olasubomi Balogun wo ile ijoba ibile ijebu ode itoro lanaa./DBC.N...
07/07/2023

Ewo aworan ibi ti won ti gbe oku ologbe Otunba Michael Olasubomi Balogun wo ile ijoba ibile ijebu ode itoro lanaa./DBC.News.Yoruba

Oni ni won yoo se eto ayeye aisun onigbagbo fun Otunba Olasubomi Balogun ti opo mo si Otunba Tunwase nile re to wa nilu ...
07/07/2023

Oni ni won yoo se eto ayeye aisun onigbagbo fun Otunba Olasubomi Balogun ti opo mo si Otunba Tunwase nile re to wa nilu Erinlu lona imodimosan ijebu./DBC.News.Yoruba

Ewo Aworan lati ibi ayeye eto isinku Otunba Michael Olasubomi Balogun ti won se nilu Eko./DBC.News.Yoruba
07/07/2023

Ewo Aworan lati ibi ayeye eto isinku Otunba Michael Olasubomi Balogun ti won se nilu Eko./DBC.News.Yoruba

Egbe awon Dokita ni Naijiria fun ijoba apapo ni ose meji lati fi ida Ogowa (200℅) kun  owo osu awon./DBC.News.Yoruba
06/07/2023

Egbe awon Dokita ni Naijiria fun ijoba apapo ni ose meji lati fi ida Ogowa (200℅) kun owo osu awon./DBC.News.Yoruba

Ijoba Bola Ahmed Tinubu so pe awon oloja yoo maa san owo ori pelu ami idanimo to ye laipe kaakiri Naijiria ki ijoba le r...
06/07/2023

Ijoba Bola Ahmed Tinubu so pe awon oloja yoo maa san owo ori pelu ami idanimo to ye laipe kaakiri Naijiria ki ijoba le ri owo na fi tun Naijiria se./DBC.News.Yoruba

Address

Festac Town

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when DBC.News.Yoruba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to DBC.News.Yoruba:

Share