
08/09/2023
Nilu Ibadan, Motunrayo lóyún fokunrin meji, loro ba di haaa boo'lo se jẹ.
Emi ni mo ni, ra oo temi ni, nitori emi ni mo se ikomo. Aseyin wa aseyin bọ, Ọrọ dii ile ise radio oriyomi Hamzat nibi ti iwadi DNA ti fihan gbangba gbangba pe, ko seni to loyun ninu awon mejeeji.
Haaaaa. Obìnrin!!! Motunrayo baye je. Leyin ti awon ọkùnrin méjèèjì tuuu obitibiti owo jọ fun DNA test. Lo ba gbe ọmọ Ọbà f'ọsun.
Taaa waa lo loyun ngba na? Ni Motun ba ni Buoda Afizi Operator ti n gbe ni Omi Adio ni oooo. Haaa! Mewa nsele o
Aye toto fun! Ekun rere ìròyìn ohun nbe lori eto kọkọrọ alatẹ, ni agidigbo efeemu.
©asiwajubumxy