
06/04/2025
April 6, 2025
Ilu Ibadan, Ipinle Oyo.
OMOWE OMOLOLU OLUNLOYO, TOJE GOMINA IPINLE OYO NIGBAKAN RI, JADE LAYE NI OWURO KUTUKUTU ONI.
Oloogbe Omololu Olunloyo je gomina ipinle Oyo atijo, labe egbe oselu National Party of Nigeria (NPN)
laarin October. 1 si December. 31, 1983 (kio to dipe ijoba oloogun Buhari - Idiagbon le won wole)
Oloogbe Omololu je olukoni fun eko Isiro, o si tun je Balogun fun ilu Oyo alaafin. Wakati die loku ki oloogbe Omololu Olunloyo pe eni aadorun (90 years) si akoko igba iku re.
Ki Olodumare bawa bu ororo itunu sokan ebi, ara, ojulumo ati awon ore ologbe na.