Nation TV

Nation TV Nationtelevisionofafrica was established in the hearing of people [email protected]
(1)

OBA ADEYEMI AWOSOLA ORISADEMILADE AKOKO AKA BABA JEJE OBA AARE APAPO IRUNMOLE ABOMOLA AGBAYE CELEBRATE  OGUN FESTIVAL IN...
08/09/2025

OBA ADEYEMI AWOSOLA ORISADEMILADE AKOKO AKA BABA JEJE OBA AARE APAPO IRUNMOLE ABOMOLA AGBAYE CELEBRATE OGUN FESTIVAL IN GRAND STYLE WITH GOOD PEOPLE OF ONDO CITY

Ogun lakaiye
Ọsin mole
Ogun alada méjì
Ofi okan sanko
Ofi okan yena
Ọjo ogun nti ori oke bo
A*o ina lo mu bora
Ẹwu eje lowo
Ogun onile owo
Ọlo na ola
Ogun onile Kongun kongun Ọrun
Olomi ni ile feje we
Olaso nile fimo kimo bora
Ogun apon leyin iju
Egbe lehin omo kan
Ogun meje logun mi
Ogun alara ni n gb’aja
Ogun onire a gb’agbo
Ogun ikole a gb’agbin
Ogun ila a gb’esun isu
Ogun akirin a gb’awo agbo
Ogun elemono eran ahun ni je
Ogun makinde ti dogun leyin odi
Bi o ba gba tapa a gb’aboki
A gba ukuuku a gba kemberi
Nje nibo lati gbe pade ogun?
A pade ogun nibi ija
A pade re nibi ita
A pade re nibi agbara eje ti nsan
Agbara eje ti ndeni lorun
Bi omi ago
Bomode ba ndale
Ki o mase da Ogun
Oro Ogun leewo
Ara Ogun kan go go go!

゚ fans

20/08/2025

Egungun BOTITO OSI LAYE MON 2025

19/08/2025

OSUN OGIYAN ANNUAL FESTIVAL
ITA OSUN ILE-IFE


fans

EGUNGUN BOTITO OSI LAYE MON TI ILU ODE OMU OSUN STATE  KA JO PEJU SE TAMODUN LASE ELEDUMARE  ゚               Òmìnira ọmọ...
19/08/2025

EGUNGUN BOTITO OSI LAYE MON TI ILU ODE OMU OSUN STATE KA JO PEJU SE TAMODUN LASE ELEDUMARE

゚ Òmìnira ọmọ Odùduwà

the sacred ceremony of:Idijo Oye and Arapron for OBA IFAYOMI BABATUDEDate: 17th August 2025 Location: World Obatala Holy...
18/08/2025

the sacred ceremony of:

Idijo Oye and Arapron for OBA IFAYOMI BABATUDE

Date: 17th August 2025
Location: World Obatala Holy Temple, Igbo Itapa, Ile-Ife, Osun State

Join us as we honor OBA AWURELA OBATALA AGBAYE and seek His divine blessings.

Ase

May Obatala's divine presence guide and bless us all

fans ゚

16/08/2025

EGUNGUN DANAFOJURA LIVE AT WORLD SANGO OYO FESTIVAL 2025



Àsàyorùbátv 2 Oyo Legacies The park Management Oyo State

15/08/2025

ETUTU NI A HUN FI EGUNGUN SE SI ARI ILU
LATI ENU AKOGUN AWO OF IWO LAND

*Installation Ceremony: Chief Olawumi Osunbiyi Omisunmare Akogun Awo of Iwo*Congratulations to Chief Olawumi Osunbiyi Om...
12/08/2025

*Installation Ceremony: Chief Olawumi Osunbiyi Omisunmare Akogun Awo of Iwo*

Congratulations to Chief Olawumi Osunbiyi Omisunmare Akogun Awo on this momentous occasion! The installation ceremony, led by the esteemed Araba Ifatayo Afolabi and attended by devoted Ifá and Òrìṣà devotees from Iwo Osun, marks a significant milestone in his spiritual journey.

May the blessings of the Almighty, the guidance of Ifá, and the love of Osun be upon Chief Olawumi Osunbiyi as he embarks on this new role. May his leadership and wisdom inspire and uplift the community.

ASE OOOOO

10/08/2025

EGUNGUN OMOLEWA NI ILU IWO OSUN

゚ fans

08/08/2025

OSUN OSOGBO FESTIVAL 2025


fans

Address

Number 1 Ile Aperin Adekile Ibadan
Ibadan

Opening Hours

Monday 09:00 - 17:00
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00
Saturday 09:00 - 17:00
Sunday 09:00 - 17:00

Telephone

+2348170382766

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Nation TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Nation TV:

Share

Category