21/12/2025
📢📢IROYIN YAJOYAJO🔈🔉
Ijamba ọkọ ofurufu kan lo ṣẹlẹ ni yajo_yajo, awọn oṣiṣẹ papa'kọ ofurufu ṣọ wipe ko si ẹni to ye ninu ijamba naa. Gbogbo awọn to wa ninu ọkọ ofurufu yi ni wọn ba iṣẹlẹ ijamba naa lọ.
Gẹgẹbi awọn asoju kọrọyin ile-iṣẹ papa'kọ ofurufu naa ti wi atẹjade orúkọ àwọn to ba iṣẹlẹ naa lọ ni wọn fi ranse si ile iṣẹ redio igbohun safẹfẹ ti ile iṣẹ ONIKOYI kariaye.
Orukọ wọn ni wọnyi:
********************
1. ISORO AYE RẸ
2. ITIJU AYE RẸ
3. ẸGAN AYE RẸ
4. IBANUJẸ AYE RẸ
5. IJAKULẸ AYE RẸ
6. ẸKUN ATI OSE AYE RẸ
7. AISAN NINU AYE RẸ
8. AINI ATI ÀÌRÍJẸ
9. IKU AIT'ỌJỌ
10. IDAAMU
11. IKỌSILẸ
12. OSI AYE RẸ
13. IKU ỌKỌ ATI IKU AYA
14. IKU ỌMỌ
15. AFAITO NINU AYE RẸ
Mase kọminu tabi beere fun oku wọn, nitoripe gbogbo wọn lo jona kọja sisọ pẹlu ọkọ ofurufu naa.