Vision radio ibadan

Vision radio ibadan The ability to think about or plan the future with imagination or wisdom

Kí ló wá dé tí Oriyọmi Hamzat àti Gudugudu á ń pariwo kiri pé àwọn ni INEC mú nọ́mbà orúkọ wọn gẹ́gẹ́bí olùdíje fún ipò ...
10/09/2026

Kí ló wá dé tí Oriyọmi Hamzat àti Gudugudu á ń pariwo kiri pé àwọn ni INEC mú nọ́mbà orúkọ wọn gẹ́gẹ́bí olùdíje fún ipò gómìnà lẹ́gbẹ́ Accord ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́?
Vision radio ibadan news

May your soul rest in Peace alhaji taiwo Hassan ogogo we love you but God loves you more 😭😭😭😭
23/08/2026

May your soul rest in Peace alhaji taiwo Hassan ogogo we love you but God loves you more 😭😭😭😭

Awọn ti wọn n beere owo dọla ẹgbẹẹgbẹrun, awọn ti wọn n diye le itọju naa bii ẹni diye le ọja lori atẹ, gbogbo ẹ ni Kira...
23/08/2026

Awọn ti wọn n beere owo dọla ẹgbẹẹgbẹrun, awọn ti wọn n diye le itọju naa bii ẹni diye le ọja lori atẹ, gbogbo ẹ ni Kira ṣalaye. Ka a nibi:

Vision radio ibadan news

" Ó yẹ kí Ogogo lọ sí ilẹ̀ India fún ìtọ́jú àmọ́ kò lè wọ bàálù torí àìsàn jẹjẹrẹ ti wọ̀ ọ́ lára"Ṣé ni àwọn ọmọ Ogogo ń ...
18/08/2026

" Ó yẹ kí Ogogo lọ sí ilẹ̀ India fún ìtọ́jú àmọ́ kò lè wọ bàálù torí àìsàn jẹjẹrẹ ti wọ̀ ọ́ lára"

Ṣé ni àwọn ọmọ Ogogo ń wa ẹkún mu láti kéde pé àìsàn jẹjẹrẹ to n se Ogogo tí de ìpele kẹrin, táwọn dókítà òyìnbó sì kọ láti tọ́jú rẹ.

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn náà rèé níbí:

Eyin abiamo etewo adura ogogo oooo

Dẹndẹ ijo bẹrẹ bayii nipinlẹ OsunAdeleke fìdí Oyebamiji àti Saleem janlẹ̀, ó borí ìbò fún sáà kejìVision radio ibadan ne...
16/08/2026

Dẹndẹ ijo bẹrẹ bayii nipinlẹ Osun
Adeleke fìdí Oyebamiji àti Saleem janlẹ̀, ó borí ìbò fún sáà kejì

Vision radio ibadan news

Nigeria President Bola Tinubu don tell di Independent National Electoral Commission (Inec) and security pipo to make sur...
14/08/2026

Nigeria President Bola Tinubu don tell di Independent National Electoral Commission (Inec) and security pipo to make sure say di govnorship election for Osun State dey peaceful transparent, and credible.

Oga Tinubu tok for statement wey im Special Adviser on Information and Strategy, Bayo Onanuga, post ahead of di election wey go happun on Saturday, 15 August, 2026.

“As di pipo of Osun State dey go dia polling units to elect who go govern dem for di next four years, I call on di Independent National Electoral Commission to ensure orderly conduct of di election.

“Di election gatz dey transparent, free and fair. I urge Inec to ensure di integrity of di process.”

Govnor Ademola Adeleke, Bola Oyebamiji, Najeem Salami and Adeagbo Yemisi na some of di candidates wey dey contest.

Ìjọ Mímọ́ CCC sọ nínú àtẹ̀jáde kan ti wọ́n fi síta pé ẹ̀sùn táwọn èèyàn fi ń kan Olùṣọ́ Itunu Onadeko lórí ikú Tope Osob...
14/08/2026

Ìjọ Mímọ́ CCC sọ nínú àtẹ̀jáde kan ti wọ́n fi síta pé ẹ̀sùn táwọn èèyàn fi ń kan Olùṣọ́ Itunu Onadeko lórí ikú Tope Osoba ń tàbùkù ìjọ náà.

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn

Makinde wa rọ àwọn eeyan to n dupo òṣèlú wí pé ki wọn gbaju mọ nnkan ti wọn ba fẹ ṣe fawọn eeyan ipinlẹ Oyo, dipo bi wọn...
11/08/2026

Makinde wa rọ àwọn eeyan to n dupo òṣèlú wí pé ki wọn gbaju mọ nnkan ti wọn ba fẹ ṣe fawọn eeyan ipinlẹ Oyo, dipo bi wọn ṣe n bu oun
Vision radio ibadan news

Olagunsoye Oyinlola ni oun gbe igbesẹ yii fun anfani awọn eeyan ipinlẹ Osun.Ẹkunrẹrẹ wa nibi: Vision radio ibadan news
10/08/2026

Olagunsoye Oyinlola ni oun gbe igbesẹ yii fun anfani awọn eeyan ipinlẹ Osun.
Ẹkunrẹrẹ wa nibi:
Vision radio ibadan news

Àlàyé rèé lórí ikú tó pa Temitope Osoba, gbajúmọ̀ òṣèré tíátà tó di olóògbé:Vision radio ibadan news
05/08/2026

Àlàyé rèé lórí ikú tó pa Temitope Osoba, gbajúmọ̀ òṣèré tíátà tó di olóògbé:

Vision radio ibadan news

Address

Ibadan
200221

Telephone

+2348121940691

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Vision radio ibadan posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Vision radio ibadan:

Shortcuts

Share