Olorire t.v LIVE Baba Research

Olorire t.v LIVE Baba  Research Olorire Tv Media Entertainment is a page full of entertainment, information,and educative program
(1)

04/08/2026

Even Aduagba Garden Online tv shed more light on historical fact of Iwo let watch this video and learn

03/08/2026

Thank you boss for reposting sir

Watch the real history of Iwo where they Originated

02/08/2026

"Ṣé mọ̀ pé, gẹ́gẹ́ bí ìtàn ìbílẹ̀ Yorùbá ṣe sọ, ìlú ÌWÒ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú tí ìpilẹ̀ wọn ti wá láti Ilé-Ifẹ̀?

Láti ibẹ̀ ni àwọn baba ńlá wọn ti ṣè ìrìnàjò wá sí ilẹ̀ tí wọ́n ń gbé títí di òní. Ìtàn ni ìdánimọ̀ wa—ẹ jẹ́ ká mọ̀ ọ, ká sì bọ̀wọ̀ fún un.

Oro re lati agbenuso awon omo Oba ÌWÒ Osun State

OLORIRE TV LIVE."

02/08/2026

Hummmmm Saint Janet basiko eda bato kosi eni tole da duro

JP2026Quadri Lateef Coded loko wa lo ooooo alo ganusi aje jije amu mimu koda atun diwa le abi make i send remaninig one ...
02/08/2026

JP2026
Quadri Lateef Coded loko wa lo ooooo alo ganusi aje jije amu mimu koda atun diwa le abi make i send remaninig one si eyin fans mi ni

01/08/2026

SIA LAMO FI PA WON!! EDAKUN KINI AROJINLE TI YIN LORI ORO OLOWO IYEBIYE YII? ATI PE KABIESI WA OMO ORUMOGEGE TIA GENIUS NI WON OOOO YOU MAY NOT KNOW, WE NEED TO GIVE HIM SPECIAL AWARD ON THIS IS EVERGREEN SPEECH fans

So painful OLUBADAN PALACE PRESS RELEASE01-08-2024BREAKING NEWSLekan Alabi is dead The veteran journalist and multiple p...
01/08/2026

So painful
OLUBADAN PALACE PRESS RELEASE
01-08-2024
BREAKING NEWS

Lekan Alabi is dead

The veteran journalist and multiple press secretary to former Oyo State Governors Lekan Alabi is dead.The Abese Olubadan passed away this morning in Lagos at the age of 76 years.
Family sources say he would be buried tomorrow in accordance with Islamic rites.Details later.

Adeola Oloko
Media Aide,
Olubadan of Ibadanland

May Almighty Allah forgive his shortcomings and admit him in best of his Abode....

.....

31/07/2026

Ewa gbo itan ile ola lati enu asoju awon omo oba nilu iwo base lemo iyato larin omo ola ati omo eru....

Kilofa ti agbegbe yii da bayi OOLU FESTIVAL is taking place which is Eewo for  woman to see, edakun se obinrin loni aye ...
30/07/2026

Kilofa ti agbegbe yii da bayi OOLU FESTIVAL is taking place which is Eewo for woman to see, edakun se obinrin loni aye ni?

Because most shop was closed down afibi igba ti ose wipe obinrin nikan lo taja nilu toba ribe aki eyin iyawa ooooo

Its good to obey the custom and traditions of our dear town maya omo ale, abi did you see any iyawo alfa that has effontery to confront OOLU after their blabla on media IRO NLA iku lere ejaa

30/07/2026

Ogbon ju Agbara lo everyday episode.......
This is welcomed back message only for a wise, and a big thanks to everyone that look back on me nkankan koni se emiyin naa Adeyemi Olorire t.v LIVE Baba Research lorukomi

Address

Ibadan

Telephone

+2349055827128

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Olorire t.v LIVE Baba Research posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Olorire t.v LIVE Baba Research:

Shortcuts

Share