ALAWIYE Blog

ALAWIYE Blog A ki yin kaabo s'ori a'pere ti o n gbaruku ti idagbasoke Asa ati Ise ede Yoruba. Alawiyeblog !!!
(1)

Gẹ́gẹ́ bó ṣe sọ, gbogbo ǹkan ti ń padà bọ̀ sípò ní Nàìjìríà láti ìgbà tí ìsejọba Ààrẹ Bola Tinubu ti bẹ̀rẹ̀Kí ni èrò yin...
08/05/2026

Gẹ́gẹ́ bó ṣe sọ, gbogbo ǹkan ti ń padà bọ̀ sípò ní Nàìjìríà láti ìgbà tí ìsejọba Ààrẹ Bola Tinubu ti bẹ̀rẹ̀

Kí ni èrò yin ??

Sùúrù lọba ìwà Àgbà tó ní sùúrù,Ohun gbogbo ló ní.Bí a tí ń lọ nínú ọ̀sẹ̀ tuntun yìí,Ẹ jẹ́ ká kọ́ sùrúù.Ká fẹ̀lẹ̀ sọ̀rọ̀...
27/04/2026

Sùúrù lọba ìwà
Àgbà tó ní sùúrù,
Ohun gbogbo ló ní.

Bí a tí ń lọ nínú ọ̀sẹ̀ tuntun yìí,
Ẹ jẹ́ ká kọ́ sùrúù.
Ká fẹ̀lẹ̀ sọ̀rọ̀ nígbà tí inú ń bí wa,
Ká fi ẹ̀lẹ̀ gbọ́rọ̀,
Ká sì tún to fèsì.

Ká ní ọjọ́ rere ooo

A kú ìsinmi ooKí ni gẹ̀ẹ́sì Olùgbèjà?
26/04/2026

A kú ìsinmi oo

Kí ni gẹ̀ẹ́sì Olùgbèjà?

A kú dédé ìwòyí, láàrin Ìtẹ̀lẹ̀- Yekin àti Rotimi Salami, ta ni ó se eré Lover Boy jù?
25/04/2026

A kú dédé ìwòyí, láàrin Ìtẹ̀lẹ̀- Yekin àti Rotimi Salami, ta ni ó se eré Lover Boy jù?

Àwọn Ọba aládé láti àwọn ìpínlẹ̀ káàkàkiri nì orílẹ èdè Nàíjírà péjú sí ibi àpérò tí Gómìnà Fabura se kòkárí ẹ ní ìpínlẹ...
23/04/2026

Àwọn Ọba aládé láti àwọn ìpínlẹ̀ káàkàkiri nì orílẹ èdè Nàíjírà péjú sí ibi àpérò tí Gómìnà Fabura se kòkárí ẹ ní ìpínlẹ̀ Port Harcourt.

Ọ̀ọ̀ni ifẹ̀ ni ó jẹ́ alága ìpàdé náà gẹ́gẹ́ bí alága àwọn Ọba ní apá ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn lọ́balọ́ba ni ó péjú síbẹ̀ láti ilẹ̀ káàrọ́ọ̀ o jìí í re bíi Olubadan of Ibadan, Deji of Akure, Olowo of Owo, Oniru of Iruland, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.

Àmọ́ sá, Aláàfin ìlú ọ̀yọ́ kò sí ní ìkàlẹ̀. Kíni ẹ̀yin rò pé ó ò fá tí aláàfin kò fi sí ní ìkàlẹ̀?

BosenlọÌpàdé Ìjọba ìpílẹ̀ Ọ̀yọ́ tí Gómínà Seyi Makinde síwájú rè ti buwọ́ lu owó tó tó bílíọ̀nù mẹ́fà náírà ó dín díẹ́- ...
22/04/2026

Bosenlọ

Ìpàdé Ìjọba ìpílẹ̀ Ọ̀yọ́ tí Gómínà Seyi Makinde síwájú rè ti buwọ́ lu owó tó tó bílíọ̀nù mẹ́fà náírà ó dín díẹ́- (5.813 bilion naira) fún àwọn tí ó dín ẹgbẹrún ó dín ní ọgọ́rùn-ún ènìyàn tí ilé àti dúkiá wọn farakásá ọ̀nà tí wọ́n ńse lọ́wọ́- (circular road)

Gẹ́gẹ́ bíi kọmisọ́nnà fún ìkéde, Prince Dotun Oyelade, àwọn tí ọrọ ọ̀hún kàn yoo ní aǹfàní láti gba owó náà láìpẹ́.


Gómínà Ipínlẹ̀ ọ̀sun ti gùn lé àti yan àwọn ìgbìmọ̀ ìpolongo ìbò ìyànpada sípò lọ́la òde òní.
22/04/2026

Gómínà Ipínlẹ̀ ọ̀sun ti gùn lé àti yan àwọn ìgbìmọ̀ ìpolongo ìbò ìyànpada sípò lọ́la òde òní.

Address

Beere, Mapo
Ibadan

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ALAWIYE Blog posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share