14/09/2025
Joshua 9:22-27
Bi Joshua se so awon ara Gibeoni di Aponmi ta ati Asegi fun awon omo Israeli nitori etan ati Iro ti won se.
Loni gbogbo awon to fi etan ba o lo ni won yio di Asegi ta ati Aponmi ta fun o. Egun yio si wa si Ori awon gbogbo awon to fi etan pelu iro ba o se. Eletan ma subu niwaju re, awon opuro ki yio le gba emi re,awon eletan ki yio le gbe o subu tabi ja o bo ni irin Ajo ogo ati ni ona igbega re. Ni Oruko Oluwa gbogbo okan to je ounje re ati epo pelu iyo ti won si fi etan ba o se ki yio ri imole ogo ise rere. Iwo ni yio ma bo awon eletan, iwo ni yio ma leke awon eletan. Ni gbogbo ojo aye re, iwo ni yio ni ile(Land)ile(House) awon ota re. Amin
Happy Weekend To You All.
IN GOD I TRUST