OPELE ORO

OPELE ORO I Am OlanRewaju 'Opele Oro' AdeWusi.

A Digital Creator, Humorist, Broadcaster, Entertainer, Fashionista, Satirist, A Voice Actor And Director, A Yoruba Linguist, Culture Enthusiast And More!

12/11/2025
25/09/2025

ELEPHANT 🐘 SOLO

YAÁGBÓYAÁJÙ! Wúrà Ọmọ Oòduà!

A Tún Ti Gba Àlékún Ogún Ẹgbẹ̀rún Un Náírà (₦20,000) Sí Ẹgbẹ̀rún Lọ́nà Àádọ́ta Náírà (₦50,000)Tó Wà Nílẹ̀!

Nítorí Náà, Dípò Èèyàn Mẹ́wàá, Èèyàn Mẹ́rìnlá Ni Yóò Jẹ Àǹfààní Ìfà Àádọ́rin Ẹgbẹ̀rún Náírà (₦70,000) Báyìí!

Éèsùà!

The Link To The Episode Is 👇🏾

https://youtu.be/S9oyU-NTXs4

It Unlocks At 6!

25/09/2025

This Is No Joke!

First Ten Lucky Winners (Viewers)! Get Your Viewing Gadget Fully Charged And Stay So Glued To The Show!

Clarifications On How To Win Will Drop Soon!

Pleeeeseee, Don't Sleep On It!

YAÁGBÓYAÁJÙ!Wúrà Ọmọ Oòduà!

Éèsùà!

20/09/2025

YAÁGBÓYAÁJÙ! Wúrà Ọmọ Oòduà!

Just A Tip Here... A Tip There!

First Episode Drops Thursday September 25

Ẹ Kú Ojúlọ́nà Idán Aré Ìdárayá Ọpọlọ Alárògún Èdè Yorùbá!

19/09/2025

YAÁGBÓYAÁJÙ! Wúrà Ọmọ Oòduà!

Launch Day Fast Approaching!

Ǹ J Omidan Bím̀bọ́ Sadiq Yóò Le Fẹnu P'àkọtọ́ Bẹ́ẹ̀?

Ìpàdé D'ọjọ́ Kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n, Ọjọ́bọ, Oṣù Kẹsàn-án Yìí, Déédé Aago Mẹ́fà Ìrọ̀lẹ́ {6pm}

Ẹnà Ìtọ̀nà {YouTube Channel Link} Wà Nínú Àká Ìjúweè Mi (In My Bio}



18/09/2025

ELEPHANT 🐘 SOLO

YAÁGBÓYAÁJÙ! Wúrà Ọmọ Oòduà!

Drops Thursday Sept. 25, 6 PM

DingiMeraw Studios {YouTube}

Àgbékalẹ̀ Ètò Aré Ìdárayá Ọpọlọ Alárògún Èdè Yorùbá... Yorùbá Dùn Gbáà!

Éèsùà!

ELEPHANT 🐘 SOLO Ẹ Kú Ojúlọ́nà Idán Aré Ìdárayá Ọpọlọ Alárògún Èdè Yorùbá!YAÁGBÓYAÁJÙ! Wúrà Ọmọ Oòduà!Éèsùà!DingiMeraw St...
17/09/2025

ELEPHANT 🐘 SOLO

Ẹ Kú Ojúlọ́nà Idán Aré Ìdárayá Ọpọlọ Alárògún Èdè Yorùbá!

YAÁGBÓYAÁJÙ! Wúrà Ọmọ Oòduà!

Éèsùà!

DingiMeraw Studios {YouTube}

DingiMeraw Studios {YouTube} Is The Channel! Watch Out For This Fantastic And Maiden Episode Of YAÁGBÓYAÁJÙ! An Interest...
15/09/2025

DingiMeraw Studios {YouTube} Is The Channel! Watch Out For This Fantastic And Maiden Episode Of YAÁGBÓYAÁJÙ! An Interesting, Unprecedented Yorùbá Game Show Dropping On The 25th Of September By 6PM!

15/09/2025

YAÁGBÓYAÁJÙ!

Drops Sept 25!

Only On DingiMeraw Studios {YouTube}



Éèsùà!

Address

Felele
Ibadan
200263

Telephone

+2347035952060

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when OPELE ORO posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to OPELE ORO:

Share