07/06/2026
(IRAWO AFEFE ALAWADA GEMINI ♊️ IRAWO IBEJI) PART ONE.1
Planet 🌔 Ton Njoba Irawo yi ni mecury, irawo owo ni ama irawo yi si, Awon lrawo yi je alagbara eda, opolopo pipe ni won, Imisi olohun wa lara won (spiritual Power) okan ma nba won soro , olohun Situn Fun won ni ebun ala Lila, ninu awon Irawo ti won ma la ala pupoju ni irawo Gemini ♊️ wa, odara fun won lati se ise itusile toripe Iranse olohun ni wonje.
Irawo yi ni amasi Irawo aje toripe dandan ni owo ni odo won afi eyiti ogun aiye ba nbaja ninu won Loku.
pupo ninu won ma nni challenges awon agbalagba, ki awon oni irawo yi mu oju to oro aiye re dada won leba tete ri ogo re lo, toripe pupo ninu won ni won o kin ri oga won lo lasiko, afi eyi ti oba je oni igbinyanju ninu won,
olopolo pipe eniyan ni won olohun fun won ni opolo ati gbe oro kale, won si tun ma nwadi nkan topamo.
ise oro siso dara fun won gan toripe olohun fun won ni eburn imo oroso pupo.
Agbara awon irawo yi wa ni eyinju mejeji ati ori ahon won.
odara fun awon oni irawo yi Ki won ma wo asa funfun toripe omo elegbe po ninu won, oni Irawo yi tin ba nsa fun a*o funfun ona yio madimo.
Awon oni irawo yi won ko gbodo fi adura sise sile ati sara ki won le ba tete ri ona lo.
odara fun awon oni irawo yi ki won ma lo turare fi se adura dada toripe awon emi okunkun ma ndawo lamu pupo.
Opolopo won won ni idojuko ati isoro topo gan ni aro aiye won.
Awon oni irawo yi rere wa fun won , won o si tete ma ri erongba won, lopin igba ti won ko bati se nkan eewo irawo won abi nkan totako kadara won, ogun ko kin saba sise ni ara awon oni irawo yi toripe awon ori won le pupo awon agbalagba situn ma ndamu irin ajo aye won, lopin igba ti won bati bo ori won ti won situn lo ise awon agbalagba won tete ri ogo won lo laiye.
Ki awon oni irawo yi sora fun eewo irawo won ni sise toripe eewo irawo won ni oma wuwon se onirawo yi toba nse nkan eewo irawo re oro aiye re yio ma daru niooo, ifaseyin, amubo, alakala, ijakule, aini akojo lori owo ni yio ma sele si, ki awon onirawo yi loma nipa asiri irawo wo ati eewo irawo won dada ki won leba tete ri ogo re lo, toripe eewo irawo ni elomiran nse ti oro aiye re fidaru.
DIE NUNU EGBE IRAWO GEMINI ♊️
emere ori ofurufu
Iranse aje
Emere inu igi ogede
Egbe alara Igbo
Igi aje
Omo omi anu.
Emere omo ni oma nsaba po ninu irawo Gemini ♊️ awon egbe inu irawo yi situn ma nfi iyaje omo egbe tiko ba toju won.
Pupo ninu awon omo yi ni won ma damu awon obi won lati kekere.
Okunfa wahala sinu aiye elomiran ni wipe ko toju awon egbe re ni o nfa wahala ati idamu sinu irin ajo aiye re, iwo tio ba je omo elegbe ninu irawo yi lose awari arare dada kio ma iru egbe ti owa ati awon nkan ti wa ma fi toju won kio le ba tete ri ona lo.
Gbogbo irawo kokan niwon ni awon emi ton nba won sise oluranlowo ni , gbogbo awon spirits yi ye je fun gbogbo eda eniyan gbogbo won ni won ni nkan eewo tiwon kofe iwoti obati nse nkan ti awon emi yi kofe, odidandan ki awon Spirits yi jina sio , tiwon ba siti file jina sio inkan yio ma daru fun oni tohun ni, awon eniyan oma korira oni tohun kosi iru igbinyanju ti iru eniyan be lese koni sise fun toripe awon spirit tiwon nsise gbigba adura fun ni won ti jina si yen.
Gbogbo irawo kokan ni won ni eewo ti won, tio ye ki won jina si bena situn ni nkan tio ye ki won mase ti won fi tete de bi ogo won.
Ti eniyan ba nse nkan totako irawo re abi onfun irawo re ni eewo je iru eniyan be yio le fun lati tete de ibi ogore iwo ni kio lo se iwadi nipa irawo kio le ba mo bi wa se rin irin ajo aiye re toripe iwadi nipa irawo re ati akosejaye re ni yio so bi wase rin irin ajo aye tiko fi ni si wahala ati idamu kankan fun ninu aiye re.
Ao ni wa aiye lasan o .
FUN IWO TI OBA FE DARAPO MO WHATSAPP GROUP WA, FUN IWO TI OBA NI IBE LORI ALA ATI IRAWO JOIN PELU LINK TO WA LORI PROFILE MI.
FUN IBERE TABI IWADI NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE....MESSAGE ME PRIVATELY