Omidan Yoruba Intl Pageant

Omidan Yoruba Intl Pageant The Queen of Yorubaland (OMIDAN YORUBA) is a cultural based Pageant designed to promote Yoruba rich-

Yorùbá dùn lasá lédè ati n'ise Advertise your products and services in our special edition of OMÍDAN YORÙBÁ magazine foc...
19/06/2025

Yorùbá dùn lasá lédè ati n'ise

Advertise your products and services in our special edition of OMÍDAN YORÙBÁ magazine focusing on OJUDE OBA 2025
..fún ìgbélarúgẹ àṣà èdè àti ìṣe Yorùbá

Ọdún a y'abo fún wa o
01/01/2025

Ọdún a y'abo fún wa o

Sore sore, sọ òòrè ṣe 😒 nínú òòrè ti o fẹ ṣe, awọn ìkà kàn ti gọ pàmọ láti fí ọ ṣe ẹlẹyà 🙃 wọn máa lò gbogbo àgbàrá wọn ...
27/12/2024

Sore sore, sọ òòrè ṣe 😒
nínú òòrè ti o fẹ ṣe, awọn ìkà kàn ti gọ pàmọ láti fí ọ ṣe ẹlẹyà 🙃
wọn máa lò gbogbo àgbàrá wọn láti sọ ẹ ṣi túbú ayé 🥸
Aṣẹ̀dá yóò kúkú kò ọ yọ, ninu ìdánwò awọn ànínilara

 adeyemi Ọmọ ẹgbẹ́ agbábọọlù Borussia Dortmund bẹ kabiyesi wo láàfin
27/12/2024

adeyemi
Ọmọ ẹgbẹ́ agbábọọlù Borussia Dortmund bẹ kabiyesi wo láàfin

Ikú doroPa Jimi SolankeỌ̀run ire
05/02/2024

Ikú doro
Pa Jimi Solanke
Ọ̀run ire

Iyalode of Yorubaland, ìyáàfin Alaba LawsonÌyá dáadáa wọ ilẹ̀ sunSun re o
28/10/2023

Iyalode of Yorubaland, ìyáàfin Alaba Lawson
Ìyá dáadáa wọ ilẹ̀ sun
Sun re o

16/10/2023
Aláàfin kò tíì bu ògùrọ̀, Aṣípa n bu àgúnmu sọ́wọ́ InterpretationThe king is yet to drink palmwine, the chief is already...
12/10/2023

Aláàfin kò tíì bu ògùrọ̀, Aṣípa n bu àgúnmu sọ́wọ́

Interpretation
The king is yet to drink palmwine, the chief is already pouring medicinal powder to be used with the drink on his own palm

Wisdom
Let's learn to give respect and honor to whom its due.
The position of a King is higher than that of a chief, those in authority or superior to us should be given their befitting honour, and Don't be too forward, or else you'll be disgraced.

A kìí ṣaaju ẹlẹẹdẹ pẹẹdẹ.
A kòní kabuku Laṣẹ Èdùmàrè.

A kú ojumọ o!

Are you a Local food vendor? Do you sell Palmwine or Drinks? Do you have Cultural items for sale or you're running a Yor...
06/10/2023

Are you a Local food vendor? Do you sell Palmwine or Drinks? Do you have Cultural items for sale or you're running a Yoruba fashion store? Are you a retailer or non-profit vendors? 😍💃🏽🕺🏽🎸🪘🎷 Dm now to book a space for your brand in the December 1st Grand Finale of *Yorùbá Youth Summit* 🎪 live @ *CENTER FOR BLACK CULTURE AND INTERNATIONAL UNDERSTANDING, OSOGBO, OSUN STATE* 🪔🎊🍛🍻🍾 welcome to the state of the living spring 🫧💦... Fun igbe lárugẹ àṣà, èdè àti ìṣe Yorùbá

06/10/2023

Address

South West
Ile-Ife
110101

Opening Hours

Monday 09:00 - 17:00
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00
Saturday 09:00 - 17:00
Sunday 09:00 - 17:00

Telephone

08054792639

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Omidan Yoruba Intl Pageant posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Omidan Yoruba Intl Pageant:

Share