17/05/2026
ASEJE OLA
Afomo ori igi obi niwonba, ao lo afomo yi pelu ata ijosi merindilogun kunu dada, ao fa sinu ikoko aseje kan, ao fi se igbin lepo niyo, ao gbodo ge igbin yi o, odidi be lao se, ti aba setan kogbodo kanle mo o, ao gbele ori nkan, ao wafi iyerun osun te ifa ejiogbe si atelewo wa, ao ma pe ohun re si bayi wipe,
ohun re:
afomo olowo, afomo olese, ara igi ni afomo tinse ola tire, lodidi ni olugbo figbin tore fun ero ona, odidi owonla niki awon omo araye fi tore fun mi lati oni yi lo, ao se adura si dada, ao wada iyerun osun yi sinu aseje na, ao ropo, ao koje, odaju
For consultation or you need spiritual work.
Message me on WhatsApp
07067630726