WURA TV

WURA TV WÚRÀ TV..tiwantiwa

A radio-visual program to project cultural norms, tradition, beliefs and ethical values of Yoruba richness Coverage

Adéníyì, Orí l’ẹja fi labú, orí lọ̀kàsà rẹ fi wẹdò, Orí tó mú wáyé wùmí, orí owó, orí ọlá, Orí tó yan Àlákẹ́, ẹni bí ọkà...
27/01/2026

Adéníyì,
Orí l’ẹja fi labú, orí lọ̀kàsà rẹ fi wẹdò,
Orí tó mú wáyé wùmí, orí owó, orí ọlá,
Orí tó yan Àlákẹ́, ẹni bí ọkàn rẹ,
Orí tó pe àwọn Ọmọ Àlùbáríkà wáyé,
Orí tò ọ́ síwájú nínú ìbí, orí sọ ẹ́ dọ̀gá lẹ́nú isẹ́, orí sọ ẹ́ dàpé sìn láwùjọ.
Orí ọ̀hún tùn kádún láyọ̀.
Gbọgbọ l’ọwọ́ yọọ́ jorí, gbọgbọ ni màrìwò ọ̀pẹ̀ ẹ yọọ́ ju ọ̀pẹ̀, dandan ni kí ẹ̀gún òkèrè rẹ máa yọ jù wọ́n, Igbá ilé, kó lé, ọlá rẹ kó má lópin láṣẹ Èdùmàrè,
Bó dàmọ́dún kájọ fàìkú dẹ́gbẹ̀ra.

Músò!

Address

Ile-Jagilegbo
Iwo
232101

Telephone

+19294207136

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when WURA TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to WURA TV:

Shortcuts

Share