Aremu Akekaka

Aremu Akekaka Orisun Iroyin ti ko ni Abula

11/07/2026

Bayi ni awon omo-ologun se gba awon oluko ati akekoo ti awon afemisofo jigbe ni ipinle Oyo sils

11/07/2026

Bayi ni awon omo-ologun
se gba awon oluko ati akekoo ti awon afemisofo jigbe ni ìjọba ibile Orire sile reeee!!!!@

Ijoba ipinle Oyo ti lo wo Ile ti awon ajinigbe to ji aburo Adelabu gbe lule.
08/06/2026

Ijoba ipinle Oyo ti lo wo Ile ti awon ajinigbe to ji aburo Adelabu gbe lule.

Tani ka gbogbo bayi o:Iya principal ti awon ajinigbe jigbe lo pelu awon omo Ile iwe l'Ogbomoso tun ti jade sita pelu fid...
08/06/2026

Tani ka gbogbo bayi o:

Iya principal ti awon ajinigbe jigbe lo pelu awon omo Ile iwe l'Ogbomoso tun ti jade sita pelu fidio tuntun nibi to ti n so wipe iro patapata gbaa ni ìjọba ipinle Oyo npa.

O ni awon ajinigbe wonyi ko beere kankan, won ko soro ofin Sheria , beeni won ko beere Hilux lowo ìjọba ipinle Oyo rara.

O ni Ohun kan soso ti won beere fun ni idasile awon omo egbe awon ti ijoba ti mole.

Awon ibeere wonyi la le maa beere:

Se ijoba ipinle Oyo wa n paro ni?

Nje iya yi nsoro lati inu re wa tabi Oun ti won ni ko so lo n so loju ibon?

E gbo se o to lati da awon eeyan wonyi sile?

Olorun igba gbo ni Yinka Alaseyori ti toro aforiji lowo gbogbo omo Nàíjíríà lori Oro to so nipa ojo igbe to sele ni ipin...
03/06/2026

Olorun igba gbo ni Yinka Alaseyori ti toro aforiji lowo gbogbo omo Nàíjíríà lori Oro to so nipa ojo igbe to sele ni ipinle Oyo.

Oro yi ti wa n doju e bo, awon ajinigbe ti ji aburo Adebayo Adelabu Penkelemeesi pelu awon ibeji re gbe lo ni ilu Ibadan...
03/06/2026

Oro yi ti wa n doju e bo, awon ajinigbe ti ji aburo Adebayo Adelabu Penkelemeesi pelu awon ibeji re gbe lo ni ilu Ibadan bayi o

03/06/2026

Owo te afurasi odaran Fulani kan ti kii se omo ologun sugbon to wo a*o omo ologun ni ilu Osogbo.

29/05/2026

Nje egbe alatako to nife ara ilu wa ni Nàíjíríà nitooto abi imo tara-eni nikan ni gbogbo won nba kiri

29/05/2026

O ma wa ga bayi o!

Eyin ìjọba wa e dide lati gba awon eniyan yi sile

Awon ajinigbe to ji awon akekoo ati oluko gbe ni ipinle Oyo ti soro jade bayi o. Won ni awon ko setan lati ba awon ara I...
23/05/2026

Awon ajinigbe to ji awon akekoo ati oluko gbe ni ipinle Oyo ti soro jade bayi o. Won ni awon ko setan lati ba awon ara Ile awon ti won jigbe soro bikose ìjọba ipinle Oyo funra re.

Ohun ti awon ajinigbe yi pelu ìjọba ti so ni enikankan ko ti mo bayi.

Gbogbo ara ilu lo be ìjọba ki won jowo tete gbe igbese kiakia lati doola emi awon omo wonyi, paapa julo ti eniyan ba wo foto kan to wa lori ayelujara bayi to n se afihan awon omo kan ti won bo si ihoho pelu apa egba lara won, ( bo tile je wipe a ko mo boya aworan awon omo naa ni tabi bee ko), omije a si bo loju eni.

Address

Ikeja
Lagos
100011

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Aremu Akekaka posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Aremu Akekaka:

Shortcuts

Share