26/08/2024
Yoruba Translation of "How to use the screen sharing feature for Smart TVs.
Ṣí Mifi, Laptop àti Tẹlifìsìn sí i.
1. Turn on the Mifi, Laptop, and Television.
Yẹ̀wo ó sì dájú pé laptop náà ti sopọ̀ mọ́ nẹ́tíwọ́ọ̀kì Mifi.
2. Check and ensure that the laptop is connected to the Mifi network.
Tẹ bọtìn Input lórí rímọ́ti tẹlifìsìn >> Yan Screen Sharing
3. Press the Input button on the TV remote >> Select Screen Sharing
Lórí laptop náà, wá ọ̀rọ̀ Cast láti ìṣẹ́ ìbẹ̀rẹ̀, sì yan Connect to wireless display option >> Yan Connect
4. On the laptop, search for the word Cast from the start menu and select Connect to wireless display option >> Select Connect
Orúkọ tẹlifìsìn náà yóò hàn, yan orúkọ tẹlifìsìn náà nígbà tí ó bá hàn, sì dúró fún ìsopọ̀ rẹ̀.
5. The TV name will be displayed, select the TV name once displayed and wait for it to connect.
Ìsopọ̀ ti fẹ́ṣẹ̀rí.
6. Connection successful.