15/05/2026
So wipe:; oluwa ibukun ti o kin gbe oluwa fi fun min, oni ri ibanuje Lori omo π Ogun kotokoto pelu Ogun Koka koka ko ni je ipin reππ Oni ba won lo Irin ajo kodekode, ori re oni gba abode tomotomo ππ Ogun agbako ijanba motor ko ni je ipin reππ amin