Enny Tales TV channel

Enny Tales TV channel Enny Tales TV is all about Alo Apamo ati Apagbe in Yoruba to promote Yoruba culture in our society m

12/02/2025

Alo Apagbe lede Yoruba lati gbe Asa ati Ise Yoruba laruge.ITAN OBA ATI AWON AREWA OMO RE META.Kindly follow our page .God bless you all

12/02/2025
Eku ojo meta gbogbo eyin ololufe EnnyTales nibi ti a ti npa Alo Apamo ati Apagbe lati gbe asa ati ise Yoruba laruge,a du...
28/07/2024

Eku ojo meta gbogbo eyin ololufe EnnyTales nibi ti a ti npa Alo Apamo ati Apagbe lati gbe asa ati ise Yoruba laruge,a dupe pupo lowo gbogbo yin pata.E jowo e tubo gbe wa laruge ki eto naa Le maa tesiwaju.Thank you all

15/10/2023

*🌺IṢẸ́ NI ÒGÚN `ṢÉ* *🖊️Múra sí iṣẹ́ Ọ̀rẹ́ mi* *🖊️Isẹ́ ni afí ń dẹni gíga* *🖊️Bí akò bá rẹ́ni fẹ̀yìntì* *🖊️Bí ọ̀lẹ là á rí* *🖊️Bí a kò bá rẹ́ni gbẹ́kẹ̀lé* *🖊️Á tẹra mọ́ isẹ́ ẹni* *🖊️Ìyá rẹ lè lówó lọ́wọ́* *🖊️Bàbá rẹ́ sì lè lẹ́shin lé kan* *🖊️Bí o bá gbójú lé wọn* *🖊️O tẹ́ tán ni mo sọ fún ọ* *🖊️Ohun tí a kò bá jìyà fún* *🖊️Ṣé kìí lè tọ́jọ́ rárá* *🖊️Ohun tí a bá fara ṣiṣẹ́ fún* *🖊️Ní npẹ́ lọ́wọ́ ẹni* *🖊️Apá lará* *🖊️Ìgúpá nì ìyè kàn* *🖊️Bí aiyé bá ńfẹ ọ lónìí* *🖊️Tí o bá lówó lọ́wọ́* *🖊️Ayé á máa fẹ́ ọ lọ́lá* *🖊️Jẹ́kí o wà ní ipò àtàtà* *🖊️Aiyé á ma yẹ́ ọ sí tẹ̀rín-tẹ̀rín* *🖊️Jẹ́kí ó dẹni tí ń ràgò* *🖊️Kó o rí bí aiyé tí n yínmú sí ọ* *🖊️Ẹ̀kọ́ sì lè ṣẹni dọ̀gá* *🖊️Múra kí o kọ dáradára* *🖊️Bí o rí ọ̀pọ́ ènìyàn* *🖊️Tí ń fi ẹ̀kọ́ ṣẹ̀ rín rín* *🖊️Dákun má fara wé wọn* *🖊️Ìyà ńbọ̀ fọ́mọ tí kò gbọ́n* *🖊️Ẹkún ń bẹ fọ́mọ tí ó ń sá kiri* *🖊️Má fòwúrọ̀ ṣeré ọ̀rẹ́ mi* *🖊️Múra sí iṣẹ́ ọjọ́ ń lọ.

Address

Lagos

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Enny Tales TV channel posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Enny Tales TV channel:

Share