Yeye Agbasaga

Yeye Agbasaga Official Yeye Agbasaga page. We're live on here every first Thursday of the month, 5pm-6pm. Join Us!

04/09/2025
Gbajumo lafo More a gbe wa o Mo dupe fun aseyori inawo wa ni December 1 2024 olorun ti fi anu gba gbogbo gbajumo lafo op...
15/12/2024

Gbajumo lafo More a gbe wa o
Mo dupe fun aseyori inawo wa ni December 1 2024 olorun ti fi anu gba gbogbo gbajumo lafo ope ni fun olodunmare πŸ’ƒπŸΌπŸ’ƒπŸΌπŸ’ƒπŸΌπŸ’ƒπŸΌπŸ’ƒπŸΌ

01/09/2024

Happy birthday to you my son easy one Israel Oladokun long life and prosperity πŸŽ‚πŸΏπŸ¦πŸŽ‰ igba Odun Odun kan ninu Owo Omo alafia emi gigun pelu ifokan bale lolorun ma fi jiki e o amin πŸ™

Gbajumo lafo More a gbe wa o Mo gba ladura fun gbogbo omo Afo nile loko ati ni okere  abo olorun a dajun lori gbogbo wa ...
08/07/2024

Gbajumo lafo More a gbe wa o
Mo gba ladura fun gbogbo omo Afo nile loko ati ni okere abo olorun a dajun lori gbogbo wa ati idile enikankan wa olorun a bawa dawo iku ojiji duro ni ilu wa
Gbogbo ogun tole ma da erun ati lo si ilu abinibi wa ba wa olorun a bawa se gbogbo e lase wole
Ominale afo a gbeja gbogbo omo afo lowo awon arogo bogo je
Gbogbo wa la ma ranu gba lagbara olorun oba amin More a gbe wa oo

Iku doro iku seka iku mu eni wa lo egbo wa ebi wa omoiya wa ore wa oloye pataki nilu Afo iku o ma seka oo Chief Josiah O...
04/07/2024

Iku doro iku seka iku mu eni wa lo egbo wa ebi wa omoiya wa ore wa oloye pataki nilu Afo iku o ma seka oo Chief Josiah Oni Olowu Asiwaju ti ilu Afo jade layie huuuu😭😭😭
Gbogbo omo bibi ilu Afo a ku ara fera ku o gbogbo ebi Olowu ati ebi chief Bada e ku ara fera ku o awayie maku kosi gbogbo wa la je gbese iku
Pogodo omo Afo e joni fowo so owo po dajudaju a se gbogbo ogun to nja wa ni ilu wa e joo e ma joni gbagbe ile oo atunse Afo o dowo gbogbo wa
Gbajumo lafo more a gbe gbogbo wa oo

Iku doro iku seka iku mu eni wa lo egbo wa ebi wa omoiya wa ore wa oloye pataki nilu Afo iku o ma seka oo Chief Josiah O...
04/07/2024

Iku doro iku seka iku mu eni wa lo egbo wa ebi wa omoiya wa ore wa oloye pataki nilu Afo iku o ma seka oo Chief Josiah Oni Olowu jade layie huuuu😭😭😭
Gbogbo omo bibi ilu Afo a ku ara fera ku o gbogbo ebi Olowu ati ebi chief Bada e ku ara fera ku o awayie maku kosi gbogbo wa la je gbese iku
Pogodo omo Afo e joni fowo so owo po dajudaju a se gbogbo ogun to nja wa ni ilu wa e joo e ma joni gbagbe ile oo atunse Afo o dowo gbogbo wa
Gbajumo lafo more a gbe gbogbo wa oo

Address

Lagos

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Yeye Agbasaga posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share