AROYE Television

AROYE Television For culture &Tourism,Fashion,Society & Life Styles plus general Entertainment

Lonii,ọǰọ kẹtadinlọgbọn oṣu keje ọdun 2025, ni Gomina ipinlẹ Eko,Babajide Sanwo-Olu ṣebura wọle fawọn alaga ijọba ibilẹ ...
27/07/2025

Lonii,ọǰọ kẹtadinlọgbọn oṣu keje ọdun 2025, ni Gomina ipinlẹ Eko,Babajide Sanwo-Olu ṣebura wọle fawọn alaga ijọba ibilẹ ogun ati ijọba ibilẹ onidagbasoke mẹtadinlogoji kaakiri ipinlẹ Eko

OLOROGUN KUKU,ỌGBẸNI ỌJA TILẸ IJẸBU NI ADELE ỌBA BAYII.OUN LAṢẸ AWUJALẸ WA LẸNU RẸ LỌWỌLỌWỌ
17/07/2025

OLOROGUN KUKU,ỌGBẸNI ỌJA TILẸ IJẸBU NI ADELE ỌBA BAYII.OUN LAṢẸ AWUJALẸ WA LẸNU RẸ LỌWỌLỌWỌ

Atiku ti pada fi ẹgbẹ oṣelu PDP silẹ o
16/07/2025

Atiku ti pada fi ẹgbẹ oṣelu PDP silẹ o

Lọla Tusidee ni Buhari maa wọ kaa ilẹ lọ
14/07/2025

Lọla Tusidee ni Buhari maa wọ kaa ilẹ lọ

Ikọ agbabọọlu Chelsea ṣi n dawọ idunnu bi wọn ṣe ko patiẹ bo ọta wọn ti wọn lu PSG ni alubami
14/07/2025

Ikọ agbabọọlu Chelsea ṣi n dawọ idunnu bi wọn ṣe ko patiẹ bo ọta wọn ti wọn lu PSG ni alubami

Ikọ aarẹ ti balẹ silu London lati tẹwọgba oku Buhari
14/07/2025

Ikọ aarẹ ti balẹ silu London lati tẹwọgba oku Buhari

14/07/2025

Awujalẹ maa wọ kaa ilẹ lọ lonii,laago mẹrin.
Awọn ẹbi ọba ti fiwe lede,wọn ni kawọn eeyan pade wọn ni Ọgbagba

14/07/2025

OÒGÙN ẸSẸ̀ TÓ WÚ KÍ Ó LÈ FÀ Ao wa ewe patanmọ oojọ,ewe ejinrin oojọ,eso lapalapa pupa to pọ diẹ,egbo idagba,ewe idagba,awọ ejo t...

14/07/2025

Ni bayii, awọn ọmọ bibi ilu Yewa ti yari o koda wọn diju mọ agbari ni, wọn lawọn o nii gba ki kinni naa tun fo awọn da bayii, da...

14/07/2025

Ọrọ naa ko wọ rara lọjọ Satide ọjọ kejila oṣu yii, lọjọ naa lawọn eeyan ipinlẹ Eko fi ibo pinnu awọn ti yoo ma dari ijọba i...

14/07/2025

EYI GBENUTAN O, TALẸNTI KAN REE

14/07/2025

I gained 3,385 followers, created 10 posts and received 2 reactions in the past 90 days! Thank you all for your continued support. I could not have done it without you. 🙏🤗🎉

Address

Ikeja
Lagos

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when AROYE Television posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to AROYE Television:

Share