
29/03/2025
https://www.asejere.net/ilera-eko-%e1%b9%a3agbekale-eto-tuntun-fawon-egbe-alafowosowopo/
Lori eto ati ri daju pe tonile talejo ipinlẹ Eko lo wa ni ilera to peye, ìjọba ipinlẹ Eko labẹ iṣakoso gomina Babajide Sanwo-Olu pẹlu ajọ toun moju to eto ilera nipinlẹ naa iyẹn ajọ Lagos State Health Management Agency, LASHMA, ti ṣe to “Ilera N’Tiwa to jẹ ẹgbẹ alaj....