31/08/2026
- Àwọn èèyàn ń kú, níbo ni gbogbo owó ìrànwọ́ epo ti ijoba yọ wa, kinni anfaani rẹ sì àwọn ọmọ Nàìjíríà, oye kí jọba lé ṣàlàyé, Femi falana lo sọ̀rọ̀ síta bee
- Dínọ̀ Melaye tí bu ẹnu àtẹ lu àárẹ̀ Tinubu lórí irinajo ọṣẹ meta to rìn, ó ní aarẹ lọ fún isinmi lẹ́yìn ọpọlọpọ oko ọ̀rọ̀ àti ìbéèrè tí Atiku solu
- Tí Tinubu bá fi lè lọ sí ìpàdé àjò isokan àgbáyé, a ó fi ojú rẹ gbole a ó sì rí dájú pé gbogbo ayé mọ pe ọ̀daràn agbe ológun oloro ni, ileeṣẹ kan tó fi kalẹ sílẹ̀ amẹ́ríkà lo kéde síta bẹẹ
- Igboro tí bẹ̀rẹ̀ si dàrú pelu bí àwọn èèyàn ṣe kó firi egbò lójú gbajugbaja ọṣèré tíátà Adewale Adeoye, làwọn èèyàn bá bẹ̀rẹ̀ si gbàdúrà pé k**a ribi lagbole amuludun mo
- Ibi eerin méjì bati woya'ja koriko ibẹ niya a ma je o, iyanselodi ile iwosan okukoni LAUTECH ti n fa inira fawon alaisan logba naa o.
- Ni'le sinimọ kan l'Eko ọkùnrin kan sekọlu, fi ọ̀bẹ gun ẹṣo ẹnu ọna kan pa se èèyàn mi lese saaju kòun náà o to fida lelẹ, ki aye pe o digbà o se.
- Awọn araalu tí doola ọmọbìnrin tuntun jòjòló kan tí wọ́n gbé sílẹ̀ nínú paali ni ipo àìlera to burú gan-an ní ìpínlè Benue
- Ọ̀rọ̀ oselu lásán ni gbogbo ẹ, Bashir Ahmad fèsì lórí ọ̀rọ̀ ileeṣẹ kán ni ilẹ̀ Amẹrikà to ni kò ní saye fún Tinubu láti ṣe pàdé pò pelu àárẹ̀ Trump ati pe wọn ò foju rẹ gbole to bá wá sí ìpàdé isokan orile-ede agbaye
- Awọn Ọlọpaa fi teargass tu awọn osisẹ fẹyinti ka lasiko ti won korajọ fẹhonu han lori bi Ìjọba se n fi ẹtọ wọn dun wọn l'Eko.
- Ìdí rèé tí Dangote fi ṣe àfikún owó epo bẹntiróòlù fún ìgbà mẹ́ta láàrin ọ̀sẹ̀ kan àti ipa rẹ̀ lórí àwọn aráàlú
- Ètò Àdúa Fidau jokejo Ogogo wáye loni o, ẹbí ara, ore ati awọn akegbe gbajumo agbà osere kunrin náà lo n rawọ ẹbẹ sadua pe kOlohun seku nisinmi fun ko saforiji gbogbo ẹsẹ rẹ.
E WA GBO NTO SELE NIBI ETO FIDAU OGOGO TAIWO HASSAN TO WAYE NI ILAR...