OlaFortune

OlaFortune Lover of Humanity
Content Creator
Blogger
Digital Maketer & Brand promotion

21/10/2025

Orisun Lamba: Oduduwa mu Adiye🐓 dani wa si ile-ife lati inu Orun wa.
Ibeere: Se Broiler ni Adiye yen tabi Adiye ibile gangan.
Ibeere ni, e jo e ma sepe o🙄

21/10/2025

Orisun Lamba so wipe: Oduduwa tele chain⛓️ sokale si Ile-ife lati inu Sanmo wa.
Ibeere: Se ile-ife ko Factory to n produce chain⛓️ sinu sanmo ni? 🙄🙄

21/10/2025

Abore ilu Lamba s'ope "Oduduwa Gbe Ade👑 Wa Si ile-ife Lati Oke Orun"
: Se won produce Ade ninu sanmo ni ?🙄
Ibeere ni, e ma bu mi o 🙄

20/10/2025

Ara Ile-ife o ni Oruko Oriki bi Akanmu, Akanbi, Akanji, Also, Iyanda etc
—Oluwo ilu-iwo

Eyin Ara Ile-ife se e ni Oruko Oriki ??

20/10/2025

We Gave King Pharaoh His Name After Giving Him Crown.
His Real Name is Ifa-Ri-Awo Which Egyptians turned Pharaoh

– Olori Lamba

Oluwo of Iwoland Oba (Dr.) Abdulrosheed Adéwálé Àkànbí, Telu 1, Dr. Adedeji Adeleke and Ataoja of Osogbo, Ọba Jimoh Ọlan...
20/10/2025

Oluwo of Iwoland Oba (Dr.) Abdulrosheed Adéwálé Àkànbí, Telu 1, Dr. Adedeji Adeleke and Ataoja of Osogbo, Ọba Jimoh Ọlanipẹkun at the Adeleke family wedding.

This kind picture na headaches and body pain e dey always give awon Orisun Lamba 😄😂.
As e dey sweet us, e dey pain them 💃😄😂

20/10/2025

We Created Pharaoh's Crown👑 in ile-ife and Sent It To Him In Egypt.
We Owned Pharaoh's Crown

– Orisun Lamba

19/10/2025

Ai Rin Jina Lai Ri Abuke Okere o 🤗
Ai Rin Sumo Awon Ara Ife Lai Gbo Lamba To Kii Pompon !
Walahi, Awon Ara Ibeun Ni Awon Iyalaya Lamba Lowo Fa!

19/10/2025

Awon Ara Orisun Lamba So Wipe👇
"Oduduwa Mu Adiye🐓 Dani Wa S'aye"
: Se Poultry wa ni orun tabi inu sanmo ni?🙄

19/10/2025

Ta Lo Mo o, Ko So Fun Wa

Ilu wo ni Orisun Lamba ?

Ogbenutan o !!! !! !Ero okan awon ara Orisun Lamba ni ki gbogbo aye korira Oba Oluwo ti ilu Iwo, Telu1;  sugbon o n ya w...
18/10/2025

Ogbenutan o !!! !! !
Ero okan awon ara Orisun Lamba ni ki gbogbo aye korira Oba Oluwo ti ilu Iwo, Telu1; sugbon o n ya won lenu pe, ni se ni Oluwo sa kan fela si ni lai wo odo won, be si ni awon ara Iwo tubo n feran re si ni, awon eyan jankan-jankan na n feran Telu1 si sibe-sibe.
Eyi ni wipe, awon Aja kan gbo kiri lasa ni, Telu1 o raye won, baba n fela lo.
Won kan japoro lasan ni, Telu1 o raye won, baba n gbayi lo.
Kaaabiesiiiii oooooo 🙌

Ka so otito oro,; Se aworan yi jo Oba Alade ni ile Yoruba ?Ninu Abore Orisha, Alawo ati Oba Alade; ewo ni aworan yi jo ?...
18/10/2025

Ka so otito oro,; Se aworan yi jo Oba Alade ni ile Yoruba ?
Ninu Abore Orisha, Alawo ati Oba Alade; ewo ni aworan yi jo ?

Ibeere ni o; e jo, e ma bu mi o🙄🙄🙄

Address

Lagos

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when OlaFortune posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share