
16/04/2024
Aláké ti ìlú Ègbà
Aláké ti ìlú Ègbá Òun ni ọba Yorùbá tó ṣe pàtàkì jòlọ ní Ègbá, ìlú kan ní Abéòkúta, ní ìpínlè Ògùn, gúúsù ìwò-oòrùn Nàìjíríà. Àwon ìlú Ègbá ni Ègbá Aláké, Owu, Òkè-Ònà àti Gbagura.
Oba adédòtun Àrèmú Gbádébò III ni Aláké ti ìlú Ègbá. ó je Oba ní ojó kejì osù kéèjo odún-un àrún lé ní ẹgbàá (2005). Abí Oba Adédòtun Àrèmú ní Ojó kerìnlá osù kéèsán odún-un ẹ̀ta-lé-ní-ojì lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́wá (1943).
Alake of Egbaland. He is the paramount Yoruba king of Egba, a city in Abeokuta, Ogun State, southwestern Nigeria. Egba consists of Egba Alake, Owu kingdom rule by the Olowu of Owu Kingdom, Oke-Ona and Gbagura.Adedotun Aremu Gbadebo III (born 14 September 1943) is the current Alake of Egba, a clan in Abeokuta, Nigeria. He has ruled since 2 August 2005