
27/09/2024
Ọlọ́run ti ṣèlérí fún wa nínú Ọrọ Rẹ láti dáhùn ẹ̀bẹ̀ àti ádùrá àwọn ọmọ Rẹ̀.
Kín ló wá dé tí ọpọlọpọ wà kò rí ìdáhùn sí ádùrá wa lónìí?
Láìsí òye àwọn kọ́kọ́rọ́ tó n ṣilẹkun èsì àti ìdáhùn ádùrá, àgbàyọrí ádùrá le ṣòro fún ènìyàn. Ẹkọ yìí kún fún isiniye lọpọlọpọ nípa àwọn kọ́kọ́rọ́ wọ̀nyìí.
E lọ sí t.me/ekobibeli fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ẹ̀kọ́ náà.
Jésù l'Olúwa.