Àsàyorùbátv 2

  • Home
  • Àsàyorùbátv 2

Àsàyorùbátv 2 Ekaabo si ikanni asayorubatv ikanni to ngbé asa yoruba laruge....ikanni yi wa fun igbelaruge asa,ede ati isese yoruba .. bi orin,ewi,ikede,itan ati bebe lo

15/08/2025

Kini itumo oruko re ?
Araba ifayemi elebuibon ( Araba oluisese ìlú osogbo ) gba gbogbo awọn yorùbá atata ni imọran

15/08/2025

Isese ilé yin tẹro wipe oti parun
Ko parun ọmọ tí yóò ṣe ní Koyitide

15/08/2025

Ti a ba ri musulumi kan to fe da orisa Agboolé won nu kiwon pe wa awa niilo re

Oko iyawo elepon blueNibiti owe yen ti wa ree..epon Obo le nwo yi
15/08/2025

Oko iyawo elepon blue
Nibiti owe yen ti wa ree..epon Obo le nwo yi

15/08/2025

Gbogbo awon alfa tiwon nso wipe ke lo da awon oosa ilé yin nù se won n bayin da sọrọ yin mo ?

14/08/2025

Ìmọràn fún ọba Abdulrasheed Adewale akanbi oluwo lori ọrọ awọn eleegun nílùú iwo Oloye. Olawumi osunbiyi omisunmare ( Akogun awo ìlú iwo )

14/08/2025

Orín osun oladekoju

14/08/2025

isese lagba

14/08/2025

Ninu omi osun osogbo ti awọn alfa musulumi kan npe ni omi idoti ati hantu ti won hàn itan ìlú larubawa mu fún àwọn ènìyàn ewo lo dara ju ibeere ni óò ?

13/08/2025

Won o mójútó esin won esin elesin niwon n yonu si kiri

13/08/2025

Araba. Ifatayo afọlábí ( Araba oluisese ìlú iwo ) salaye Pataki oye jije nílè yorùbá àti ninu ijo awo

13/08/2025

Iwa wa koni ba esin wa je lori social media

Address


Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Àsàyorùbátv 2 posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Àsàyorùbátv 2:

  • Want your business to be the top-listed Media Company?

Share