Asejere Group

Asejere Group Asejere is a business magazine published from Lagos, Nigeria.

It seeks to promote commerce in South West Nigeria, and encourages hard work and showcases successful entrepreneurs in the society.

https://www.asejere.net/ajo-lawma-fowo-ofin-mu-egberun-eeyan-lekoo/
05/05/2024

https://www.asejere.net/ajo-lawma-fowo-ofin-mu-egberun-eeyan-lekoo/

Ajo to n kole-kodoti nipinle Eko taa mo si LAWMA ti so o di mimo pe awon eeyan ti iye won le ni egberun kan lawon ti fi owo ofin mu nipinle Eko laarin odun kan soso. Komisanna to n sakoso eto ayika, Tokunbo Wahab lo se bayii soro yii fun awon oniroyin lose to […]

https://www.asejere.net/awon-meji-ku-sinu-kanga-ti-won-n-gbe-labeokuta/
05/05/2024

https://www.asejere.net/awon-meji-ku-sinu-kanga-ti-won-n-gbe-labeokuta/

Meji lara awọn ọmọ orileede Benin kan, Avade Clement ati Oloogbe Achefon Edua, ti wọn n gbe nilẹ wa, ti wọn yan iṣẹ gbigbẹ kanga laayo ti pade iku ojiji nibi ti wọn ti n ṣiṣẹ oojọ wọn lagbegbe Laderin, nijọba ibilẹ Abẹokuta South, nipinlẹ Ogun, lọjọ Aje, M.....

Address

Lagos
23401

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Asejere Group posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Asejere Group:

Share