21/01/2026
Maami ejide orun yin ire ooo,iwaju ti e ko oju si ki o ma daa loo ,ki Olorun ba mi Le yinaami,e yin ti e wa fissile lati odun maarun ki olorun joor ki o ba wa tun e yin na se,maami a o ri ara wa Mo ooo,sugbon ti o ba je PE eniyan lo so okuta si arin away omo yin,ti won fi ti wa ka,ki olorun ki o dide ki o bawa segun won,ki a le ma Koko laati ma se iranti yin jeje bo omo,maami ! Oyin ni e fi pon wa,oyin le fi to wa,owun na no e fi fun wa lo ounje ninu abo kan, sugbon lehin iku yin,won ti pin abo wa leyeleye ooo,Mo wa gbadura PE bi o se PE odun maarun ti e ti laarin wa,ki olorun ba wa daa be abo ife pada so arin wa,ki o ba wa segun awon ti o nda arin wa ru,ki a le ma ranti gege bi abiamo otito ti e je, sugbon e mi nse iranti yin maami,titi aye ni ma ma se iranti yin abiamo otito,iya rere ni yin,ti o se wahala Lori omo,sugbon eni ti p ba ni ki gbogbo wahala yin Lori omo ki o jaasi asan,ki olorun gbo ogun ti won,ki o se won mo ise,ki ogun na ki o wole para para,bi omi ti nwole,ti won o ki ri ko jooaami EJIDE,e gbe orun ki esi se orun ire oo,titi aye ni iranti yin.