Atótó Arére online tv

Atótó Arére online tv Atoto Arere online tv is an indigenous and a professional online base television platform committed to promoting, preservation of Yoruba language.
(1)

Do you have something to share. Kan si 09030255999

Follow like and share the news stories from our channel

29/08/2026

Wàhálà bẹ́ sílẹ̀ láàárín àwọn ẹgbẹ́ NUJ ni Kwara.

29/08/2026

Ẹgbẹ́ PDP sọ òkò ọ̀rọ̀ sí gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ APC

29/08/2026

Ibo ọdun 2027 ni Kwara: Idamu de ba awọn oloselu, Gomina Abdulrasaq ń fa oju Hakeem mọra, ajọ eleto idibo gbe orúkọ àwọn oludije sipo gómìnà ati Igbakeji wọn jade

Hakeem Lawal ti ṣọrọ: o ni irọ ni o, emi kọ ní wọn fẹẹ fun ni Igbakeji gomina lẹgbẹ oṣelu APC, ọrọ ahesọ lasan ni
29/08/2026

Hakeem Lawal ti ṣọrọ: o ni irọ ni o, emi kọ ní wọn fẹẹ fun ni Igbakeji gomina lẹgbẹ oṣelu APC, ọrọ ahesọ lasan ni

29/08/2026

Eyi ni òun ti Daretọ ẹtọ gbálè gbata sọ nípa ètò náà

29/08/2026

Awọn Fulani yabo ọfiisi Iru Ẹkun ni Kwara, ba ọpọlọpọ dukia jẹ, wọ́n tun n dunkooko lati pa ọmọ ẹgbẹ kan

Ọmọ tí ọkùnrin yii jigbe lo fẹẹ ta ni miliọnu meje tọwọ fi tẹ ẹ ni AdamawaAkolo ileeṣẹ ọlọpaa ẹka tipinlẹ Adamawa, ni af...
29/08/2026

Ọmọ tí ọkùnrin yii jigbe lo fẹẹ ta ni miliọnu meje tọwọ fi tẹ ẹ ni Adamawa

Akolo ileeṣẹ ọlọpaa ẹka tipinlẹ Adamawa, ni afurasi James, wa bayii, ọmọde binrin ẹni ọdun mejidinlogun, (18), to jigbe lo fẹ lọọ tí na miliọnu méje Naira tọwọ fi tẹ ẹ ni abule Bai, ni ileto Yadim, nijọba Ibilẹ Fufure, nipinlẹ Adamawa.

Wọn ti gbe e lọ siwaju Ile-ẹjọ Májíréètì kan ti adajọ sì ni kí wọ́n lọ̀ọ́ sọ si ahamọ ọgba ẹwọn naa

Eyi ni bi ọgọọrọ awọn lookọ-looki nínú ẹgbẹ oṣelu APC ni Kwara ṣe lọọ pade Hakeem Lawal, ni papakọofurufu tiluu Ilọrin, ...
29/08/2026

Eyi ni bi ọgọọrọ awọn lookọ-looki nínú ẹgbẹ oṣelu APC ni Kwara ṣe lọọ pade Hakeem Lawal, ni papakọofurufu tiluu Ilọrin, lọjọ Abamẹta, Satide yii, wọn loun ni wọn fẹẹ fun ni igbakeji gomina lẹgbẹ ọhun

Wọn ni 80 miliọnu Naira, ni ijọba Kwara fún àwọn èèyàn 146, tí wọ́n jígbe ni Wọrọ, ti wọn gbominira laipẹ yii.L'Ọjọ Ẹti,...
29/08/2026

Wọn ni 80 miliọnu Naira, ni ijọba Kwara fún àwọn èèyàn 146, tí wọ́n jígbe ni Wọrọ, ti wọn gbominira laipẹ yii.

L'Ọjọ Ẹti, Furaidee yii, ni ijọba Kwara, ko owo naa fun wọn lasiko ti wọn n darapọ mọ awọn mọlẹbi nijọba Ibilẹ Kaiama, nipinlẹ Kwara

29/08/2026

Eyi ni bi awọn ọdọ to n sere idaraya ṣe lu ọlọpaa niluu Ilọrin, lasiko eto gbale-gbata

Address

Lagos

Telephone

+2349030255999

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Atótó Arére online tv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Atótó Arére online tv:

Shortcuts

Share