22/05/2025
Sir Olu Okeowo playing the organ in his private chapel during a concert he recently hosted in honor of a visiting Ghanaian choir. The hymn titled "Now Thank We All Our God" was played with much passion by Sir Okeowo and sung in the Yoruba language of the southwest people of Nigeria.
1. Afope F’Olorun, lokan ati lohun wa,
Eni sohun ‘yanu, n’nu enit’araiye nyo
Gbat’a wa l’omowo, On na l’o ntoju wa
O si nf’ebun ife, se ‘toju wa sibe.
2. Oba Onibuore, Ma fi wa sile lailai,
Ayo ti ko lopin, on ‘bukun y’o je ti wa
Pawa mo n’nu ore, to wa gb’aba damu,
Yo wa ninu ibi, l’aiye ati l’orun.
3. K’a f’iyin ohun ope F,olorun Baba, Omo
Ati Emi Mimo; ti o ga julo l’orun,
Olorun kan lailai, taiye at’orun mbo
Be l’O wa d’isiyi; beni y’o wa lailai.