OlaJesu Gospel Tv

OlaJesu Gospel Tv Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from OlaJesu Gospel Tv, TV Channel, Omu Aran.

29/06/2026

MAJẸMU TO NBẸ NINU IBALOPỌ:
!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!
1. Ibalopọ jẹ adehun (agreement) larin eniyan meji, okunrin ati obinrin.
2. Ibalopọ jẹ imunlẹ ti eniyan ki saba ka sí.

EWU TO WA NINU IBALOPỌ:
Ọpọlọpọ lo ti kan àdánwò nipasẹ Ibalopọ.

Bi iye awon ti o bá ní Ibalopọ tabi ti won ba ọ ni Ibalopọ ba ṣe pọ tó bẹẹni awọn àjòjì ogun yíò ṣe pọ to ninu aiye rẹ.

1. Ogun ṣi ogun.
Ọpọlọpọ idile ni won ni ogun ìpìlẹ, ogun ìpìlẹ ni ogun ti ki tete sẹ nitori ogun tó ní gbongbo ni.

Ogun ìpìlẹ yi ni ọpọ okunrin gbe pade obinrin to ba ni Ibalopọ.

2. Egun sí egun.
Ibalopọ jẹ adun iṣẹju kekere, eleyi to le ba ayọ aiyeraiye jẹ tabi ti o le fa egun ti eniyan ko ni le bọ ninu rẹ.
Gen 49:3-4.

GBA ADURA YI TẸLE MI.
===================
1. Ifaya kan aya eleyi to mu ogun ati egun dé bá aiye mi, Olorun ẹ fi anu gba mi loruko Jesu.

2. Majele Ibalopọ, tó sọ mi sinu àìsàn ẹmi, ẹjẹ Jesu kò wo mi san loni loruko Jesu.

3. Ogo mi to sọnu nipasẹ Ibalopọ odi, ẹmi mimọ ẹ ba mi se awari rẹ loni loruko Jesu.

4. Ogo mi to fi ara pa nipasẹ Ibalopọ odi, ẹjẹ Jesu ba mi wo ogo mi san loni loruko Jesu.

5. Ogo mi ti obinrin tabi okunrin àjòjì ti gba lọwọ mi nipasẹ Ibalopọ, ẹmi mimọ ẹ gba fún mi pada loni loruko Jesu.

6. Ninu ide Ibalopọ, agbara Olorun ko tu mi sílẹ̀ loruko Jesu.

7. Ibalopọ igba aimọ to fi aiye mi sinu ogun, ẹjẹ Jesu kò tu mi sílẹ̀ loruko Jesu.

8. Olorun ẹ mu mi bori aṣiṣe mi igba aimọ loruko Jesu.

9. Omi ara mi ati ẹjẹ ara mi, ẹ gba iwosan loni loruko Jesu.

10. Olorun ẹ sanu fún mi loni loruko Jesu.

AMIN AMIN AMIN LORUKO JESU.

28/06/2026

Watch this testimony
And join us
You're the next to testify

28/06/2026

Ni ojo kini si ojo Keta osu keje.Ni dede ago merin irole.
E DARAPO PELU WA

28/06/2026

Join us on Wednesday, 1 st Thursday 2nd and 3rd Friday July by 4pm

13/06/2026

ASIRI OGUN TO N JA NIGERIA

07/06/2026

Prayer for the beginning of the week

02/06/2026

Join My live stream by 4pm for the God of our fathers Revival program.

Address

Omu Aran

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when OlaJesu Gospel Tv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share

Category