Kaftan TV Yoruba

Kaftan TV Yoruba E káàbò sí oju opoo weebu ayélujára KAFTAN TV Yorùbá. 482 DTH ATI 132 DTT STARTIMES DECODER.

Fun Èto tó kún fún ogbón | Ìròyìn àsìkò| Sinimá| Orin| ati bee bee lo.

KAARO OJIIRE
09/09/2024

KAARO OJIIRE

E darapo mo Balogun Tajudeen ati Afolasayo Amusat Lábála Bose nlo pelu alejo Paul Adeagbo bi won se nsoro lori Aseyinwa Iwode Lorileede Naijiria Lórí ìkànnì ...

Lori ètò àkànṣe fún idibo ipinle Imo, Kogi ati Bayelsa lórí ọjọ́ kọkànlá oṣù kọkànlá ọdún 2023.A dúpẹ́ fún Ọlọhun fún àṣ...
11/11/2023

Lori ètò àkànṣe fún idibo ipinle Imo, Kogi ati Bayelsa lórí ọjọ́ kọkànlá oṣù kọkànlá ọdún 2023.

A dúpẹ́ fún Ọlọhun fún àṣeyọrí

07/09/2023

Ọlọ́run má jẹ kó kan wá tomotomo

28/08/2023

Gba ìmọ̀ràn yí yẹ̀wò

23/08/2023

Èwo ló yẹ kí obìnrin múra fún nínú ìrìnàjò ìgbéyàwó àti ayẹyẹ ìgbéyàwó??

12/08/2023

Ẹ jẹ́ ká ṣàmí àdúrà

11/08/2023

Má f'ojú kéré ẹni tí ń bọ̀ lẹ́yìn....
Kò ṣeni tó mọ ilẹ̀ tí yóò mọ́la

10/08/2023

Èrò ẹ̀dá lè má jẹ́ èrò Ọlọhun

E máa wo ikanni KAFTAN TV YORÙBÁ lori startimes decoder 132DT482DTH

17/06/2023

Má jẹ́ kí ọ̀rọ̀ tàbí ìwà èèyàn mú ọ gbàgbé àlá rẹ

09/06/2023

Ọdún keedogbon rèé tí mo ti ń ṣeré orí ìtàgé àti àgbéléwò - Lanre Adediwura.

KỌ́ ẹ̀kọ́ láti ara ìrírí arákùnrin yí.

Lanre Adediwura

08/06/2023

N JẸ́ Ẹ mọ MIDE KUTI nínú eré WURA???

Oh! You know how disappointing he could be🤣?
Broda Mide can be so funny right??
Let's have him on the show today between 3pm and 4pm

Stream it it live on Limex World tv

https://limex.tv/kaftan_tv_yoruba_yor (KAFTANtv Yoruba)

23/02/2023

Àwa la wà níwájú!

Address

Adewole Adebayo Square, Barracks Road, GRA
Ondo
351001

Telephone

+2349032774373

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Kaftan TV Yoruba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share