Pepe Ariya TV

Pepe Ariya TV Advertise your product's or services on our program. For more information, contact Abiodun Adesina on 08060091102

18/06/2026

Makinde ló sọ ọ̀rọ̀ yìí níbi ìwọ́de tó wáyé nílùú Ibadan láti pè fún ìtúsílẹ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ tó wà ní àkàtà àwọn ajínigbé, èyí tí VDM léwájú rẹ̀
https://www.bbc.com/yoruba/articles/cwy0dqzwq3eo

18/06/2026

Gomina Seyi Makinde sọ pe "inu mi bajẹ lori iṣẹlẹ yii tori emi naa bimọ.
Ìbànújẹ nla lo jẹ fun mi nǹkan tó ṣẹlẹ̀ sí àwọn ọmọ wa.''
Ẹkunrẹrẹ iroyin wa nibi: https://www.bbc.com/yoruba/articles/cwy0dqzwq3eo

18/06/2026

Wo awọn nkan ti ọlọpaa ba ninu ile Suri Ilupeju :-
Ibọn Pump-Action kan
Ibọn Single-Barrel kan
Ibọn Single-Barrel Cut-to-Size kan
Ibọ ilewọ ti wọn gbelẹrọ meji
Ibọn ilewọ Double-Barrel ti wọn gbelẹrọ kan
Ọta ibọn mẹtalelogun
Ọta ibọn AK-47 mẹjọ
Yatọ si awọn ibọn yii, ọlọpaa ni ohun tun ri awọn ọkọ lakata rẹ bii
Ọkọ akero Mazda to ni nọmba iforukọsilẹ FFE 08 XB;
Ọkọ akero Hummer kan to ni nọmba MUS 246 CK;
Ọkọ akero BAW kan to ni nọmba iforukọsilẹ KTU 688 YG;
Ọkọ akero Toyota kan
Ọkọ akero Toyota kan to ni nọmba idanimọ BDG 117 YK;
Ọkọ akero Toyota kan to ni nọmba idanimọ BRS 842 TW;
Ọkọ Sienna kan to ni nọmba idanimọ L*D 68 CJ;
Ọkọ Ford Sharon kan to ni nọmba idanimọ FKJ 39 EW;
Ọkọ Sienna kan to ni nọmba idanimọ BDG 986 SA;
Ọkọ Toyota Previa kan
Yatọ si awọn ọkọ yii,ọlọpaa ni oun tun ri awọn alupu nibẹ bii alupupu Suzuki Inazuma Power Bike kan, to fi mọ awọn alupupu Honda ti ko ṣiṣẹ.
Ekunrere:- https://www.bbc.com/yoruba/articles/czxq79693gdo

16/02/2026

With BBC News Africa – I'm on a streak! I've been a top fan for 9 months in a row. 🎉

07/01/2026

Ikirun Agunbe Aku ara feraku😥

01/01/2026

Inu pọpọ-sinsin ọdun ni awọn ara ilu naa wa bi ọpọ ṣe n mura lati lọ si ile ijọsin fun isin aisun ọdun tuntun, nigba tawọn janduku agbebọn ọhun ya wọ ilu.

Address

Osogbo

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Pepe Ariya TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Pepe Ariya TV:

Shortcuts

Share