OROLU MEDIA TV

OROLU MEDIA TV Good day my dear followers both home and diaspora we are here to make Audience know the value of what you have or what you're selling. thanks

bring your work, products or News to OroluMediatv let the worlds see.

08/10/2025
07/10/2025

Gbó gbò Arọbafin Oju tiyin OLUFON lo LAdé. OLUFON Lo Nile . Ẹse Kabiesi Fori Ade... KABIESI OOOOOOO.

fans ゚viralシ

06/10/2025

Anabi Abasido at OLOKINNI ONE YEAR ANNIVERSARY..... fans ゚viralシ Saheed Osupa

OLUFON GRACES OLOKINNI OF OKINNI’S FIRST ANNIVERSARY AS ROYAL FATHEROkinni, Egbedore Local Government, Osun StateSaturda...
05/10/2025

OLUFON GRACES OLOKINNI OF OKINNI’S FIRST ANNIVERSARY AS ROYAL FATHER

Okinni, Egbedore Local Government, Osun State
Saturday 4th October, 2025
www.ifonorolu.org

The Paramount Ruler and Permanent President of Irepodun/Orolu Traditional Council, His Royal Majesty, Oba Peter Oluwole Ipadeola Ilufemiloye, Akinyooye III, the Olufon of Ifon-Osun, Orolu Kingdom; Deputy Chairman, Osun State Council of Obas, on Saturday honoured the invitation of His Royal Highness, Oba Kazeem Oyekunle, Ojo-Kinimofisomo II, the Olokinni of Okinni in Egbedore Local Government Area of Osun State, as Royal Father of the Day at the colourful celebration of his first anniversary on the throne. The event, held at Okinni, was a grand occasion that brought together traditional rulers, government functionaries, community leaders, business moguls and well-wishers from within and outside Osun State.

In his royal capacity, the Olufon of Ifon-Osun joined other eminent people to celebrate Oba Oyekunle’s one year of peaceful and progressive reign over the people of Okinni. His Majesty’s presence added great prestige to the event as he felicitated with the celebrant for his steady leadership and commitment to the development of his domain. The Olufon’s attendance further demonstrated his continuous support for unity, harmony, and collaboration among traditional rulers across Osun State.

The celebration was also attended by members of Irepodun/Orolu Traditional Council, His Royal Highness, Oba Yusuf Omoloye Oyagbodun, the Elerin of Erin-Osun, and His Royal Highness, Oba Ashiru Olatoye Olaniyan, the Olobu of Ilobu, among others. The atmosphere was filled with joy, cultural displays, and goodwill messages as Chieftaincy titles were conferred on dignitaries, including the Oluomo of Ifon-Osun, Orolu Kingdom, Alh. Tairu Oyedeji Ola-Egbon (Legacy Group of Investments). People took turns to eulogize the Olokinni for his exemplary leadership within just a year on the throne.

E-signed

Akeeb Adekunle YUSUFF
The Chief Press Secretary to Olufon of Ifon-Osun, Orolu Kingdom and the Aremo Obatala of the Universe fans ゚viralシ

19/09/2025

OBADA MARKET IFON OSUN

-----Sept. 19th, 2025--------

ADÉ ÀDÍKÚNKí ntó tẹ̀ síwájú , ó yẹ ká kọ́kọ́ mọ àwọn ìran wo ni wọ́n npè ní Aládikún Ọmọ Alád...
15/09/2025

ADÉ ÀDÍKÚN

Kí ntó tẹ̀ síwájú , ó yẹ ká kọ́kọ́ mọ àwọn ìran wo ni wọ́n npè ní Aládikún Ọmọ Aládénlawẹ̀ Aládé e sẹ́sẹ́ẹfun.

Gbogbo ìdílé tí wọ́n bá nkì ní oríkì yí ní ilẹ̀ Oótù , Ọmọ Ọbàtálá ni wọ́n. Ifọ́n Òròlú (Ifọ́n-Ọ̀ṣun) ní ìpínlẹ̀ ọ̀ṣun ni àgbájọ wọ́n wà . Orí Olúfọ́n àti Ọmọ Baba rẹ̀ míràn lẹ ti lè rí Adè Sẹ́ṣẹ́ẹfun ní Ilẹ̀ Yorùbá .
Àdíkún Ọláọsa Akọgun Ẹ̀rùjẹ́jẹ́ ni Ọba àkọ́kọ́ ni Ifọ́n. Aó maa sọ ìtan Ifọ́n tó bá di ọjọ́ iwájú .

Ibi à nlọ ò kúkú jìnnà , ibi à nyà ló pọ̀ .
Ọdún 1562 ni Aláàfin Ajíbóyèdé jẹ ní Ìgboho kò pẹ́ tó jẹ ni Ọ̀yọ́ ṣégun Nupe, ò sì dá ọdún Bẹrẹ sílẹ̀ .Ọdún yìí ni wọ́n fi nṣe àjọdún ọdún titun àti oun ọ̀gbín pẹ̀lú ìrántí àwọn Akọni tó ti sùn lógun .

Lásìkò tí à nsọ yìí, gbogbo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìlú ni wọ́n wá bá Ọ̀yọ́ ṣe àjọyọ̀ Ọdún Bẹ̀rẹ̀ àkọ́kọ́ . Kódà tó fi di Ọ̀la ni Ìlú Ṣakí ma nṣe ọdún yìí náà tó bá ti wolé dé lọ́dọọdùn.

Àrọ́bá jẹ́ ká mọ̀ wípé , Adé pọ̀ tí Olúfọ́n jogún lọ́wọ́ Ọbàtálá . Lára wọn ni Odù-adé(Ọba Adé) , Adé sẹ́ṣẹ́ẹfun , Adé Arí àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ .

Aláàfin Ajíbóyèdé ránṣẹ́ sí Ọba Olúfọ́n tó wà lórí oyè nígbànáà tí orúkọ rẹ̀ njẹ́ Ẹ̀míolú Olúmogbè (Ó jẹ ní Ọdún 1524-1576) wípé kó bá òun fi Adé kan ránṣẹ láti fi ṣe Ọdún Bẹrẹ tí wọ́n sẹ̀sẹ̀ dá sílẹ̀ . Ẹ má sì gbàgbé wípé , ogun tí Ọ̀yọ́ kojú fún ọ̀pọlọpọ̀ ọdún pẹ̀lú Nupe ló fa àì ní Adé ní àsìkò náà .

Ọba Ẹ̀míolú Olúmogbè ló wolé tó gbé adé kan ránṣẹ́ sí Aláàfin Ajíbóyèdé nínú Adé Àdíkún , adé náà sì ni Aláàfin rí dé ṣe Ọdún Bẹrẹ .

Láti Ìgbà náà ló ti jẹ́ wípé Ọba Olúfọ̀n nìkan ni wọ́n gbà láàyè nínú gbogbo Ọba Ilẹ̀ Yorùbá tó le dé adé wọ Ààfin Ọ̀yọ́ níwájú Aláàfin .

Kò sí oun tó birú níbẹ̀ tí Olúfọ́n bá gbé adé fún Aláàfin . Ọmọ Ọbàtálá ló gbé Adé fún Ọmọ Ògún. Ẹ lọ sinmi ariwo .

fans ゚viralシ

Address

IFON OSUN
Osogbo

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when OROLU MEDIA TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share