09/10/2025
📢 Public Appeal on Fun Radio
We are calling on the Ogun State Government, our Senator, and the Honourable Member of the House of Representatives representing Ogijo/Likosi and Simawa under Sagamu, to urgently stand up for the repair of the Likosi–Simawa Road and the road behind the Redemption Camp (Redeemed Church).
These roads are in terrible condition, causing daily hardship for residents, worshippers, and businesses in the area. The situation is unsafe, economically damaging, and long overdue for attention.
The video was recorded by concerned citizens. We need action now! Let our voices be heard. 🚧🛣️
📢 Ìkéde Àwon Ará Ilu Lórí Fun Radio
A ń pè sí Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ogun, Sẹ́nétọ̀ wa, àti Olórí Ilé Aṣòfin Àpapọ̀ tó ń ṣojú Ogijo/Likosi àti Simawa ní a bẹ̀ Sagamu, kí wọ́n ba wa dá sí àtúnṣe ojú ona opópó Likosi títí dé Simawa àti ojú ona opópó tó wà lẹ́yìn Redemption Camp (Sọ́ọ̀ṣì Redeemed).
Ojú Ona Opópó wọ̀nyí ti bàjẹ́ gan-an, ó ń fa ìṣòro kíkankíkan fún aráàlú, àwọn Ara Ilu ati awon osise, àti àwọn oníṣòwò. Awon omo Ile Ẹ̀kọ́, ìlera, àti ààbò àwọn ará Ilu wa, wà lórí ewu ní gbogbo ọjọ́.
Ẹ jọ̀ọ́, ẹ gbọ́ ohùn wa – a fẹ́ Atunse Ona yi ni kiakia! 🚧🛣️
1 ̀Ogun