
15/07/2025
,,,,,,,,,,,,,,,,,,,,, IJINLE AGBARA OLORUN,,,,,,,,,,,,,,,,,,
🌛🌛🌛🌛🌛🌛🌛OSUPA🌜🌜🌜🌜🌜🌜🌜
MOKI GBOGBO WA PATAPATA KU ISE ONI OLORUN A PINWA LERE, A WA LORI ORO OSUPA TI MO NSO LO LANA NIPA WIPE YATO SI IMOLE TI OSUPA B FUN WA NI AYE NJE IWULO MIRAN TUN WA TI A NRI LARA OSUPA????? IWONBA ENIYAN PERETE NI WON DAHUN IBEERE WA, E SE ADUPE WIPE E NFI OKAN BAWA KALO, EYIN ENIYAN OLORUN IWULO TI OSUPA NSE FUN O PO KOJA IMOLE TI O NTAN FUN AYE, OPOLOPO MA NSOPE OPO MERIN LODI ILE AYE MU IRO PATA. NI, OPO EYO KAN SOSO LAYE NI, AYE TI E SI NWO YEN KONI IGUN KANKAN AYE RI ROBOTO BI EYIN NI O DABI OSAN O WA DURO SORI OPO KAN SOSO, OSUPA NIPA TI O NKO LORI OPO EYO KAN SOSO YEN, ORI OPO EYO KAN SOSO TI AYE WA YII LO FUN-UN NI ANFAANI LATI LE MAA YI BIRIBIRI ORO PO NIBE OMI OKUN TI NRO KIRI ISE OSUPA NI, OORU (HEAT) TO YE KO MAA MU NILE AYE KII SE KEKERE SUGBON OSUPA A TI GBA OPOLOPO RE SARA , EYIN OLUWA LOGO, TEKBIR ALLAHU AKBAR, IWULO OSUPA PO GIDIGIDI SUGBON KII SE GBOGBO IBE YEN NI MO NLO,
NKAN TO FA ORO OSUPA TI A NSO NI WIPE KILOFA TI OPOLOPO ETO ADURA TABI AAJO TI AWON ENIYAN NSE KO DAHUN MO TABI KI A SOPE KO SISE DARADARA BI WON SE LERO ? SE E RANTI ??? IBE NI ORO OSUPA TI WOLE MO NPADA BO