Ìgbìyànjú The - Effort

Ìgbìyànjú The - Effort Our core values:
🎙️ No Equality No Humanity
🫱🏿‍🫲🏾 Feeding the needy elderlies
🧑‍⚕️ Fit - Health Tips & Advice
ní èdè Yorùbá

09/26/2025

Eyi ni bi Onisese se gbe ade le new Olubadan lori

09/26/2025

Wow Olubadan tutun dobale fun ara ilu ni igba ikeyin........

09/26/2025

Elegantly, Obalufe and Olori Ashley representing our 001 Oonirisa olori gbogbo oba ile Ootu Yoruba at the coronation ceremony Of our newly enthroned Olubadan of Ibadanland, Oba, senator kabiesi Rashidi Ladoja, the 44th Olubadan of Ibadanland. In attendance, we have alafin oyo and emir of iwo land

Aku orire oo as  Ladoja is now 44th Olubadan of Ibadan land. Ki ìgbà yin tuwa lara, sir,  Senator, powerful Oba Rasheed ...
09/26/2025

Aku orire oo as Ladoja is now 44th Olubadan of Ibadan land. Ki ìgbà yin tuwa lara, sir, Senator, powerful Oba Rasheed Adewolu Ladoja.

09/26/2025

🙏🏾🙏🏾🙏🏾Aiye o ni ta epo🔴 si aṣọ ala wa o. SWAG YI NA TI PỌJU...

Breaking, a gbo pe awon ebi baba Oyotunji ti fe ready lati se ejo lori iku baba won
09/25/2025

Breaking, a gbo pe awon ebi baba Oyotunji ti fe ready lati se ejo lori iku baba won

09/25/2025

If these Agodoyo Islamic fanatics continue ab*sing Oonirisa on my page, I'll start again on owoade and reminding then of iwa ibaje awon babanla won ooooo. Although, I prefer to cease fire completely as unity, development of my people and love between awon oba wa are what I want.

09/25/2025

Thank you for this interview. Religious intolerance must cease on our land if we are to move forward to a better, well developed and prosperous nation

Ẹ jẹ ka ki Olubadan pe wọn ku ọjọ́ ibi oo.. It is a happy birthday and another glorious day in the life of one of our fa...
09/25/2025

Ẹ jẹ ka ki Olubadan pe wọn ku ọjọ́ ibi oo.. It is a happy birthday and another glorious day in the life of one of our fathers and well-meaning Obas, Senator and powerful king, Olubadan of Ibadanland. Kemi ola gun and may you live long on the throne of your forefathers. Happy birthday, Sir!

Oro bi ekun o ni sele ni ile wa oo 👉🏿 Laughing moment of 001 Oonirisa & Olubadan. Choose your circle wisely, as your gro...
09/25/2025

Oro bi ekun o ni sele ni ile wa oo 👉🏿 Laughing moment of 001 Oonirisa & Olubadan. Choose your circle wisely, as your growth and development are determined by that.

To my well-meaning people, please read, the post I made today concerning our 001 Oonirisa olori gbogbo Oba ile Ootu Yoruba lapapo without mentioning Alafin or Agodoyo on my post, yet the Agodoyo still came and abused Oonirisa. Not that I am bothered about it, but they can't abuse Oonirisa on my page without me throwing laughable tantrums at Owoade and their babas in general. I am writing this for only the well-meaning people, not that I care about you munafikis, alabosi, onilara, and suduers.

As Olórí Ọba Ootu Yoruba in seclusion, Ire gbogbó lamodun. Gbogbo oun ti a ba nwa n'ire, apa wa o ka.. Àṣẹ Amin AmenWe a...
09/25/2025

As Olórí Ọba Ootu Yoruba in seclusion, Ire gbogbó lamodun. Gbogbo oun ti a ba nwa n'ire, apa wa o ka.. Àṣẹ Amin Amen

We are getting ready as we will be supporting over 100 needy elderlies at Olojo Festival with feeding the street seyitobalese's fees

Address

Sugar Land, TX
77478

Telephone

+18323239553

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ìgbìyànjú The - Effort posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Ìgbìyànjú The - Effort:

Share